Ni iru akoko yi opo ile ise nla nla ni won ngbaradi ati se akosile asekagba ise iriju won fun odun ti nlo sopin yin… Beeni opo osise ile ise wonyi ti a ti fun ni gbedeke nibi ise won ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Bi Ere BI Awada Oorun Odun 2016 n lo Ibi Ati Wo….
Ni iru akoko yi opo ile ise nla nla ni won ngbaradi ati se akosile asekagba ise iriju won fun odun ti nlo sopin yin… Beeni opo osise ile ise wonyi ti a ti fun ni gbedeke nibi ise won ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...
Read More »ayangalu Comments Off on A té o náá…
A té o náá. Hee, a té o náá. Kí o tún ara e té o. Awo kì nlé ikún. Awo kì nlé ejò o. A té o náá kí o tún ara e té. Awo kì nsúré gun igi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ejo kini oruko ewe yi
ayangalu Comments Off on Orunmila ni awure emi naa moni awure
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku isimi opin ose adura wa yio gba o, ori buruku koni je tiwa o ase. Laaro yi mo nfe ki a mo iwulo ewe yi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oriki Ori
Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ikoja aaye pelu aimo iwon ara eni…
Mejeeji ko papo amoo won maa n wo tele ara wo leyin ni. Yorubo won ni, ikoja aaye nii mu ki fulani o kiri odo iyan. Aimo iwon ara eni naa nii sii muki abuke o ko ise atun’ko se. Emo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi Ninu Odu Ifa OGBEYONU,
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin Ku isimi oni emi wa yio se pupo re laye o ase. Loni mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi ninu odu ifa OGBEYONU, ...
Read More »Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, mogbaladura laaro yi wipe eledumare koni jeki enikookan wa jaye inira loni ase. Laaro yi mo nfe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi ninu odu ifa ...
Read More »ayangalu Comments Off on “Kíní ó ye’kú nùn l’Órí Awo?
Èjì Òyè Ifá ní ó ye’kú nùn l’Órí Awo What will avert death away from Awo? Èjì Òyè Ifa will avert death away from Awo.” ~Owó
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more