Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ...
Read More » 
		ayangalu Comments Off on Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi
Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ti o ba ka iwe yii fi ara e han
Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu. E seun.
Read More »ayangalu Comments Off on Owonrisogbe – Ifá Naa Ki Bayi Wipe: Biijo biijo…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku orire osu Ògún tuntun to bawa layo ati alaafia, osu naa yio sanwa sowo, somo, sile kiko, moto rira, ire oko/aya ati aiku baale oro yio ...
Read More »ayangalu Comments Off on Eríwo Yà! Eríwo Yà!! Eríwo Yà!!!
Ṣí Gbogbo Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀, Ní òní yìí (ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, oṣù kejèe 2019) ni ìgbẹ́jọ́ tó bẹ̀rẹ̀ ní ìtàdògún tó kọjá lọ (Tuesday, 9th of July 2019) parí (tí ìdájọ́ sì wáyé pẹ̀lú) lórí ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Má Jẹ Àkàrà Ọ̀ràn Sími Lọ́rùn
Aruku madẹgbẹ má jẹ àkàrà ọ̀ràn sími lọ́rùnAruku madẹgbẹ Mo sé ní ìwúre fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní òwúrọ̀ tòní wípé àlejò ọ̀ràn tó ma kóbá èmi àti ẹ̀yin kò ní bá wa ní àlejò ooo
Read More »ayangalu Comments Off on Ìwúre Toni
Ikú tó yọ lóòré ńkọ́ Àrùn tó yọ lóòré ńkọ́ Ẹjọ́ tó yọ lóòré ńkọ́ Òfò tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí kọ̀wun, àyà mí kọ̀wunMoti jẹ kọ̀ǹkọ̀ mo ti kọ̀ Owó,aya, ọmọ,gbogbo ire tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí gbàwun, àyà mí gbàwunMoti jẹ ...
Read More »ayangalu Comments Off on O lápátí
Kò tirẹ̀ lápátíKò sí ẹni lè gbà pe kí wọ́n dojú ìbọn kọ òwun Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun ti a wọ inú rẹ̀ yí wípé ògún lákayé kò ní dojú ìjà kọ èmi àti ẹ̀yin tọmọ tọmọ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..
Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOrí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOlú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díNítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ Mo sé ní iwure fún ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iba Eleiye
Orunmila wi Awo tan.Ifa mi Awo ku mi Bara Agbonmiregun.Ifa ni nibo ni Awo ku si?Mo ni o ku awon Ajagaruwa.Mo ni o ku awon Alsgbede orun ko mero ileke.Mo ni o ku Okoko sii wele. Ifa lo di obiri Mo ni ...
Read More » Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more