Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀Òòró gangan laa bósùnÒsùn dé o Alàwòrò Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò ní ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Ní Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa
Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀Òòró gangan laa bósùnÒsùn dé o Alàwòrò Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò ní ...
Read More »ayangalu Comments Off on Tàgiiri
Tàgiiri ma yí nìsó Ara rẹ lokùn Ara rẹ ní ajé gbe ńso
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹ̀yẹ̀lé
Yiyẹ̀ lonyẹ́ ẹ̀yẹ̀lé, Ayé ayẹ̀ wá kàlẹ̀, Rirọ lonrọ àdábà lọrún, Ayé yio rọrún fún wá jẹ̀,
Read More »ayangalu Comments Off on Ifá naa ki bayi wipe: Osa Alawure (Osa Otura) – Otua Meji
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, adura wa yio gba, ori buruku koni je tiwa loni o Àse. Mo nfi akoko yi nki gbogbo onisese patapata kaakiri agbaye wipe aku aseyori odun ifá agbaye o , a ku odun a sin ku iyedun o, emin wa yio se pupo re ninu ola ati idera lase Eledumare.
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹ Káàbọ̀ sí oṣù tuntun
Oṣù Òkúdù á yanjú gbogbo ohun tí ó ń dùn wá lọ́kàn Ẹnikẹ́ni ò sì ní bá wa du’re ayọ̀ wa. @AlamojaYoruba
Read More »ayangalu Comments Off on Bí ewúrẹ́ bá bojú wo ẹ̀yìn
Á fi èpè fún elépè Mo sé ní ìwúre wípé gbogbo ọ̀tá tí o bá ń robi tàbí sebi sí èmi àti ẹ̀yin lẹ́yìn yoo ma fí orí ara wọn gbe láṣẹ Ọlọ́run Olódùmarè Àsẹ Eu oro para que qualquer inimigo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọmọ: Ẹ̀bùn Edùmarè !
Ẹ̀bùn Edùmarè ni ọmọ Ẹ̀rí ìfẹ́ rẹ̀ sí wa ni wọ́n Èdùmàrè à ń bẹ̀ ọ́ Bá wa wo àwọn èwe yè Fi wọ́n fún àwọn tí ń wojú rẹ fún ẹ̀bùn wọn Má ṣe jẹ́ kí wọ́n kú mọ́ ...
Read More »Ohun to wa leyin Ofa!
Read More »ayangalu Comments Off on Asiri àwo kintú,
Asiri ẹ̀tú kintú, Iwọ iwori bógbè IFA, Ki owá bo asiri mi, Iwọ iwori bógbè. Mogbá ládùrá wipè loni ọjọ àbámẹtá asiri gbógbó wa koni tu kotobó lailai,gbogbo abá ti aba da loni yio jẹ mimusẹ, Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀. Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀.
Read More »Lolade Comments Off on Alaafin Sets The Record Straight, Refutes Ooni’s Claim On Yoruba Ancestral Ties With Igbos
SCRIPT OF THE LETTER PUBLISHED ON PAGE 29 OF THE NIGERIAN TRIBUNE ON THURSDAY, MAY 2, 2019. In recent time, I have been inundated with calls and even visits to my Palace on a recent Video Tape showing His Imperial ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more