Home / Tag Archives: Ewi Toni

Tag Archives: Ewi Toni

ewi

Video: Ewi Rendition

@oluwavalu: We made this video for U.K based musical Artiste @caleb_kunle It was shot during the Covid-19 lockdown in Oworo and i am proud at what we were able to achieve given the little resources at hand then. I Directed ...

Read More »

Ewi Toni: Egbe APC iba oooo

Egbe ofo Toko coronal wo Nigeria Egbe abamo ti ki tele ofin. Akuse egbe tin pin rice agolo Kan fun eniyan mewa

Read More »
ewi

Ewi Toni: Toju Iwa Re Ore Mi 

Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ...

Read More »
Yoruba Festival

Ewi Toni – 20.03.2016

Ojumo ti mo Eda ti ji saye Eda ti ko mose asela Ka ji ni kutu hai Ka gbegba pota Iya Akanke nko O ti re werenjeje Baba Talabi da O ti sare re kutuwenji Ki ni n le wa? ...

Read More »