Àwòrán; Toke Makinwa jáde ní àrà òtò ní orílè èdè South Africa láti pàdé SA OAP àti àwon t’ókun lórí àjò SA tí ó ń bò lónà.
Toke Makinwa sèsè dé sí orílè èdè South Africa láìpé yí gégé bí ó se ń rìn káàkiri àgbáyé láti di gbajúgbajà ònkòwé. Ìmúra rè yanilénu nígbà tí ó wo aso aláwò pupa férééfé (pink Gert Johan) àti bàtà ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more










