Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola À ṣẹ kò sééyan táyé ò lé bá ṣọ̀tá, ó tún hàn pé wọ́n le bínú òkú ọ̀run , yàtọ̀ sèèyan tí wọ́n jọ ń wà láyé. À bí kín ní ...
Read More »
AbubakarMuhd Comments Off on Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola À ṣẹ kò sééyan táyé ò lé bá ṣọ̀tá, ó tún hàn pé wọ́n le bínú òkú ọ̀run , yàtọ̀ sèèyan tí wọ́n jọ ń wà láyé. À bí kín ní ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ebenezer Obey ò kú o–Asojú ẹgbẹ́ Obey
Ebenezer Obey ò kú o–Asojú ẹgbẹ́ Obey Ó dà bí ẹni pé àwọn èèyàn kìí fẹ́ rán aṣọ wọn níbi tó gbé ya mọ́ lóde òní. Ìtọ pinpin àti àríwísí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀ ló kù tí wọ́n ń mójútó, bọ̀kílẹ̀ èyí ...
Read More »ayangalu Comments Off on Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú
Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú Minisita fun ipinle ati eto ise ni orileede yii, Agbejoro agba Festus Keyamu ni awon Asoju sofin ranse si ni ilu Abuja lonii. Won fi saarin, won si bere si ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò
Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò– Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti ilú Àbújá ti yẹ àga mọ́ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Adams Oshiomhole nídìí Ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni mẹ́tà ti adájọ́ Eunice Onyemanam sójú fún ni wọ́n fẹnu ...
Read More »ayangalu Comments Off on Orisirisi: Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC
Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC Àjọ tó ń gbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà EFCC sọ pé àṣírí àwọn ayédèrú òṣìṣẹ́ ẹgbẹ̀rún kan àjọ tó ń ṣàkóso ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ nípìńlẹ̀ Kwara ti tú sí àwọn ...
Read More »ayangalu Comments Off on O̩wó̩ pálábá 185 nínú o̩mo̩ e̩gbé̩ òkùnkùn ségí l’Eko
O̩wó̩ pálábá 185 nínú o̩mo̩ e̩gbé̩ òkùnkùn ségí l’EkoYínká Àlàbí Komisona olopaa ni ipinle Eko, Ogbeni Hakeem Odumosu tenu moo ipinle Eko ko ni faaye gba egbe okunkun rara. Eyi lo faa to fi tete pakiti mole lati gbogun ti ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìdájọ́ ikú kò pọ̀jù fún gbogbo afipá bánilòpọ̀ – Ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn
Ìdájọ́ ikú kò pọ̀jù fún gbogbo afipá bánilòpọ̀ – Ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn Àgbáríjọpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọmọnìyàn bíi mẹ́rìnlà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ti korò ojú sí ìwà ìfipábánilòpọ̀ àti ìṣekúpani tí àwọn obìnrin ń kojú láwùjọ. Nínú ìpàdé àwọn oníròyìn tó wáyé lópin ...
Read More »ayangalu Comments Off on Auxiliary, ata dùǹdú rẹ̀ ń fínmú — Ìjọba Ọ̀yọ́ dúnkookò
Auxiliary, ata dùǹdú rẹ̀ ń fínmú — Ìjọba Ọ̀yọ́ dúnkookò Ó dà bí ẹni pé orí tí yóó súpó, kìí jẹ́ kí ti ọlọ́kùnrùn ó yè ni ọ̀rọ̀ fẹ́ dà báyìí fún asáájú ìgbìmọ̀ tó ń ṣe àkóso gárèjì ọkọ̀ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀
Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ A kìí gbélé ẹni ká fi ọrùn rọ́ ni a ti ń gbọ́ tipẹ́ tipẹ́, sùgbọ́n kín wá ni ká ti pe tirúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà yìí tó wáyé ní ààfin Ọọ̀nirìṣà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣe àfihàn àwọn afurasí tó jí ìbejì Akeugbagold gbé ní ìlú Ìbàdàn
Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣe àfihàn àwọn afurasí tó jí ìbejì Akeugbagold gbé ní ìlú Ìbàdàn Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, àṣẹgbé kan kò sí, àsepamọ́ ló wà.Ni báyìí, kélé òfin ti mú àwọn ọ̀daràn tó jí àwọn ìbejì Alhaji Taofẹẹq ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more