Gégé bí ìtàn se so è yun-ùn tí won pín sí orí èro ayélujára (IG) ti Joro Olumofin. Òdómobìnrin tí ó gba òrékùnrin rè tí kò n’ísé l’ówó gbé nínú ilé rè ní Eko padà délé láti ìrìn-àjò ...
Read More »Yearly Archives: 2017
Àwòrán Afárá(Bridge)tí ó já tí won sì ti kò sílè ní ìlú Ilorin .
Afárá (Bridge ) yí ni òjò ti gbá dànù láti bí osù díè séyìn látàrí òjò nlá tí ó rò tí àwon ìjoba kò sì se nkankan si . ònà alágbàdo ni afárá yí wà . Nígbà ...
Read More »Àwòrán ìsìnkú Tagbo Umueke ní ìpínlè Anambra .
Òré Davido, tí ó n jé Tagbo Ifeatuchukwu Umueike ni ó sùn re ní ogún’jó osù kèwá odún, 2017 (20/10/2017) ní ìlú tí a bi sí. Ní ìjoba ìbílè Osumenyi ní ìpínlè Anambra . Àwon òré ...
Read More »Òdómobìnrin odún mókàndínlógún pín àwòràn ilé tí ó rewà tí sugar daddy rè rà fun .
Òdómobìnrin odún mókàndínlógún tí ó tún jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) ti gba àwon òdóbìnrin ní ìmòràn wípé kí won múra sísé kí won sì gbàgbó nípa èróngbà olórun sí won nígbà tí ó n ...
Read More »Òdómokùnrin kan ní orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè látàrí wípé àwon ebí rè kò gbà kí ó fé ìyá omo rè .
Òdómokùrin kan ni orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè léyìn ojó díè tí ó pín nípa àwon ebí rè tí kò gbà fun kí ó fé ìyá omo rè….
Read More »Bitcoin breaks through ₦2.16 Mln ($6k), Market Cap Now Exceeds ₦36 Trillion ($100 Billion)
Bitfinex, the greatest volume BTC/USD exchange, broke the ₦2.16 Mln ($6,000) barrier earlier today and has been joined by all the major exchanges. At press time, the price tag on Bitcoin had reached ₦2.16 Mln ($6,041) according to Coinmarketcap.com, causing its market capitalization to ...
Read More »Nneoma Nkechi àti Rochas Okorocha pín àwòrán won tí ó ti pé .
E wo àwòrán tipétipé Gómìnà Rochas Okorocha àti ìyàwó rè tí ó rewà, Nneoma Nkechi Rochas Okorocha. Àgbà wá búra bí èwe ò bá se ó rí…
Read More »Please help, I slept with 2 guys in 24 hours, I’m pregnant! Is there a way to guess the father?
My name is Am***, 29, I have now been seeing two men together for over 6 months and I never had the cause to regret it or feel remorseful until now. I’m 3 months pregnant and I’m in a dilemma ...
Read More »Àwòrán ìgbéyàwó ògbóntarigì olórin afòròdárà tí orúko rè n jé Gucci mane .
Àfòròdárà (Rapper) Gucci Mane àti Keyshia Ka’oir se ìgbéyàwó alárinrin tí ó jé wípé ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won wò ó n’ílé l’óko lórí èro amóhùnmáwòrán.igbéyàwó náà rinlè gan tí ó fi jé wípé àwon ènìyàn jàkànjàkàn ...
Read More »