Home / Art / Àṣà Oòduà / Oko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna

Oko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna


Oko ofurufu helicopter eleyii ti awon ologun n lo fun idanileko lo jabo ni ibuba awon omo ologun to wa ni Kaduna leyin iseju mewaa to gbera soke.

Ilu Abuja lagbo wi pe oko ofurufu naa n lo ki lala re to lo soke to pada wale loju kan naa mbe.
Gege bi itopinpin Olayemi Oniroyin, awon eniyan bi meje ti won wa ninu baalu naa la gbo wi pe won parun.

E ku etileko fun akotun iroyin.

Orisun Iwe Iroyin

About Lolade

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

general

Army General Expose the Foreign Missions Behind Boko Haram And Bandits In Nigeria