Home / Art / Àṣà Oòduà / O se o Eledua ! Alaafia ti n pada sara Oliseh
oliseh

O se o Eledua ! Alaafia ti n pada sara Oliseh

Akonimoogba egbe agbaboolu Super Eagles, Sunday Oliseh, si wa ni ile iwosan niluu Belgium nibi to ti n gba itoju lowo.
Iroyin tuntun to te Olayemi Oniroyin lowo lati enu awon dokita isegun oyinbo ti n toju re fi ye wa wi pe alaafia ti n pada si ara Oliseh, eni to je okan lara egbe agbaboolu Julius Berger tilu Eko lodun 1990.

Ti e ko ba gbagbe, ojo kejilelogun osu kewaa odun yii (22/10/15) ni won gbe Oliseh digbadigba wo ilu Belgium nigba ti ipo ilera re bere si ni yoro koja bo ti ye.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti