oyeku
Photo credit - Olasegha-fambidun Awogbemi-peter Babalawo and artist Eji Ogbe pen and ink drawing

Oyeku meji

Oyeku mo ba e mule ki o mase dami,
Inu bibi eru ni n pa eru,
Edo fufu iwofa ni n pa iwofa,
Adia fun ofua obi ti iku n pa elegbe re ni iwofa ti o n pa won ni rewerewe,
Won ni ki ofua obi o rubo,
Ofua obi rubo ni iku ba ye Lori re, lo ba yin awo, loni :bi iku ba n pa elegbe mi!
ototo loyeku yoo ma sa mi si ototo.
Gbogbo ki yoo ba won ku iku ajoku o aseeeeeeeeeeeee…….

About admin

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ifa on sex

Ifa on Sex and Sex Positions With Owomide Ifagbenusola