Òsùbà fún Civilian Joint Task Force (JTF) ní Gubio ìlú kan ní Borno tí won d’ènà tí won sì pa méta lára àwon ikò agbésùmòmí Boko Haram nígbà tí isé ń gbòde lówó.
Àwon olùdáàbòbò gba ìbon àti òkadà padà lówó won…
🇧🇩☢️Bangladesh launches first power unit of the Rooppur Nuclear Power Plant — built together with Russia. The head of Russia’s Rosatom calls the launch of Bangladesh’s first nuclear power plant a historic event for the country.