Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè Anambra.
Gbajúgbajà òsèré , Obi Madubogwu kú ní omo odún métàdínláàdóta (47).
E wo àwòrán ìsìnkú rè.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

