Home / Art / Àṣà Oòduà / “Èmi ni mo ni é” Adesua Etomi ni ó sobéè fún Banky W nígbà tí ó pín àwòrán ìgbéyàwó won.

“Èmi ni mo ni é” Adesua Etomi ni ó sobéè fún Banky W nígbà tí ó pín àwòrán ìgbéyàwó won.

   Àrídájú ti wà báyìí wípé Adesua Etomi àti Banky W ti di tokotayà, gbajúgbajà òsèré bìnrin ni ó sèsè pín àwòrán won yí tí ó sì so irú ìfé tí ó ní fun, nse ni ó dàbí eni wípé won bí won fún ara won ni, won bí won láti níìfé ara won ni, nítorí náà ìfé tí won ti ní síra ti pòjù.

Banky W tí ó pín àwòrán kan náà ti se ìlérí láti níìfé rè títí di ojó ogbó.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti