Àwon ikò ológun ni inú won n dùn tí won sì n yò léyìn tí won pa ejò nla rògbòdò kan níbi tí won tèdó sí .
Àwon Akoni yí ya àwòrán pèlú eranko afayàfà yí nígbà tí inú won n dún .
Ọ̀rọ̀ Yorùbá ti ọjọ́ òní – Èse Ọrọ miiran fun Èse ni Ológìní, Músù tabi Ológbò Yoruba word of the day: Èse Another word in Yorùbá for Èse (Cat) is Ológìní, Músù or Ológbò.