Gabriel Emmanuel Chinoso, tí ó jé Akékòó olódún mérin tí se Akékòó eka èkó onímò nípa ohun amáyé rorùn tí a mò sí electrical engineering ní ilé-èkó gíga Tafawa Balewa university, Bauchi ni ati gbó wípé òkú sí inú odò ìwè ní Yankari.
Ó rì s’ómi nígbà tí ó n wè lówó ní ojó àìkú tí alukoro àwon olópàá tí a mò sí Dsp kamal Abubakar nàà ti jérìí si.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

