Jọ̀gbọ̀dọ̀ lẹ̀fọ́ lorúko ti Ifá ńjẹ́
Ẹ̀rọ̀ wọ̀ loyèe tẹ̀tẹ̀
Ayé kọpá
Ẹ̀sọ̀ lo gbà
Èle tán láye
Ẹ̀rò ló kù
A dífá fún Ìrókò Ẹlujù
Tí wọ́n ní ó máa so okùn
Kó tún máa so oyindẹ
Ìrókò kó o má so èle
Ẹ̀rọ̀ were nÌrókò ń so
Ẹ̀rọ.
Courtesy: Moyo Okedeji
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

