Home / Art / Àṣà Oòduà / Odu Ifa: Obara eguntan

Odu Ifa: Obara eguntan

Obara eguntan
I I
I II
I II
II II

Ifa so wipe ki alaniyan yi ni aforiti gidigidi lori ohun ti o difa si yi.

Obara eguntan, egun kun, ajapa-nlele
A difa fun agunfon-abi-osulolo
Nijo ti I nbe l’oko egba gun
Nijo ti I n be l’oko egba gbon
Ebo na pe ko ma se
Riru ebo
Titu ope
Aseyinwa, aseyinbo
Agunfon-abi-osulolo wa do-olokun
O wa donide
O wa da-alala ile agunfon-abi-osulolo
Iwure
Ire gbogbo ni Tomini…
Owo alakedun ki se ‘gi..

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

Prof. Moyo Okediji Turns A Day Older today

Today is the birthday of professor Moyo Okediji. Let’s join hands to wish him longevity and sound health. 256 odu ifa Signatures © Ifa University Photo/Moyo Okediji 256 odu ifa Signatures © Ifa University Photo/Moyo Okediji