Aya = Wife
Ìyá Afin = Queen
Ayaba = Queen
Yèyé Ọba = Queen mother
Olorì = King’s wife
Omidan =Beautiful woman
Ọmọge = Young fashionable woman
Ìyàwó = Wife
Erelú = Female Chief
Ìyálọjà = Market Leader
Ìyá Àdínnì = Female Muslim Leader
Ìyálájé = Female title (Successful female entrepreneur)

By Adébóyè Adégbénró
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

