Home / Author Archives: admin (page 34)

Author Archives: admin

Henrietta Kosoko lori GbajumoTV

 

Read More »
Gbenga_Adeboye

Se Gbenga Adeboye lo ko Wale Dada nise sorosoro?

Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lori eto naa ni won ti beere lowo enikan to ti fi igba kan dije ...

Read More »
yemi

Yemi Osinbajo: Ori taa fi sewe

Igbakeji Aare, Yemi Osinbajo nigba to wa nile iwe alakobere Corona School, Lagos.  Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taa ba dagbalagba.

Read More »
pasuma

Foto lati ibi ayeye ojo ibi Pasuma to waye lonii

Wasiu Alabi Pasuma, Oganla Fuji 1, pe eni odun mejidinlaadota (48) lonii. Ayeye ojo-ibi IbaWasila waye ninu ile re to kale si Omole niluu Eko nibi ti awon eniyan Olorun, ore ati ojulumo ti pejo lati ba yo ayo ojo ...

Read More »
Seyi_Makinde

E wa wo ohun ti oludije ipo gomina n se lagbala pelu aya re.

Eng Seyi Makinde, okan ninu awon oludije ipo gomina nipinle Oyo, labe egbe oselu SDP ninu eto idibo odun 2015 to waye ni yii pelu aya re.  Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin lati enu awon to sun mo eni ti ...

Read More »
Wole soyinka

Atelewo eni ki i tanni i je

Awon Yoruba bo, won ni amukun-un eru re wo, o ni oke le n wo, e wole. Ojuse awon obi ki i se lati pese ohun ti awon omo won ba n fe nikan, bikose lati sakiyesi iru ebun ti ...

Read More »
ayederu

Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu?

Orisun iwe Iroyin Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon iroyin bayii, a kan maa n gbo ...

Read More »

Foto: Saheed Osupa Mr Designer

Awon eniyan oba ni Osupa ti mura tan lati gbe awo orin re tuntun jade. E le ka iroyin naa NIBI. Eniwee, mo sakiyesi wi pe awon aso okeere maa n mu oju osupa dabi odomode nigba ti awon aso ibile ...

Read More »
fila

Fila o dun bi ka moo de…

Oni fila yii

Read More »
bitie

Idi pataki meta ti ko fi ye ka maa fi ehin je eekanna

1. Ehin le yingin tabi ki die kan lara ehin wa: Nigba mi-in ti a ba n gbiyanju lati fi ehin ge eekanna wa, ehin wa le lura won lojiji, eleyii si le fa ki ehin yingin legbe kan tabi ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb