Home / Author Archives: Awoyemi Bamimore (page 19)

Author Archives: Awoyemi Bamimore

mayday

A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.

A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.* Osù ìségun àséwolè ni yóò jé. A kò níí se gégé ibi, béè ni ìkònà burúkú kò níí kò wá. Nínú Osù yìí, a ó ségun òtá ilé àti tòde, a ó réyìn ...

Read More »

Toolz pèlú àwon tí won se àseyege ní BBnaija ti odún yí, Miracle, Nina, Cee-c Alex àti Tobi.

 Àwon ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Nina, Alex, Cee-c Tobi àti Miracle ni won ti ya àwòrán pèlú asojú beat FM, Toolz lóòní gégé bí won se bèrè ìrìn àjò won léyìn ìgbélé won.

Read More »

Omokùnrin Ronke Oshodi Oke, Richmond se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè.

Ní ìsàlè ni Àwòrán ayeye ojó ìbí Richmond, omokùnrin gbajúgbajà Òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Ibironke Ojo Anthony, tí a mò sí Ronke Oshodi Oke. Omokùnrin tí ó rewà, tí ó se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè, ...

Read More »

ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé òsèlú APC ni won ti kí Ààre orílè èdè yí tí a mò sí Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi.

Ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé APC ni ó ti kí Ààre Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi. Bauchi tí ó jé òkan Lára àwon gbòógì tí ó máa n gba àlejò Buhari láti ìgbà tí ó ti di Ààre .

Read More »

Davido ti pín àwòrán tàtúù míràn tí ó yà.

Láìpé yí ni Davido pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram láti pín àwòrán àti ìtàn ti tàtúù tí ó sèsè yà sí apá tí ó pè ní “30BG” kí ó tó di wípé ó fé se ...

Read More »

Cee-c pèlú Toolz àti Yaw.

Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Cee-c ti ya àwòrán pèlú Yaw ti Wazobia FM àti Toolz ti Beat FM lénìí nígbà tí won se àbèwò sí won.

Read More »

Omobìnrin tí won ti ń wá láti ojó mélòó séyìn, èyí tí ó fi ilé-èkó sílè láti tèlé Òdókùnrin kan ní ìpínlè Delta.

Àwon ebí akékòó bìnrin kékeré tí ó sonù láti bí ojó mélòó séyìn ni a ti gbó wípé arákùnrin kan ni ó wá gbe ní ilé-èkó léyìn isé òòjó náà . Omobìnrin tí ó jé akékòó ní ilé-èkó Okpe grammar ...

Read More »

Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto .

Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto . Ìyá yí pọ̀ Ó ju omi òkun lọ Èdùmàrè Ìwọ tó o dá Ráábí aláṣọ Dákun má gbàgbé Ráábí eléwé Èdùmàrè ṣàánú mi Iná tó ń jó tálákà ní Nàìjíríà Ó dájú pé ó ju ...

Read More »

Omo ìbàdàn

Omo ìbàdàn Ìbàdàn mèsi ògò, n’ílé olúyòlé. Ìlú ògúnmólá, olódò kèri l’ójú ogun. Ìlú ìbíkúnlé alágbàlá jáyà-jáyà. Ìlú Àjàyí , ò gbórí Efòn se fílafìla. Ìlú Látóòsà, Ààre-ònà kakanfò. Ìbàdàn Omo ajòro sùn. Omo a je ìgbín yó, fi ìkarahun ...

Read More »

Oríkì ìbejì

Oriki Ibeji: Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb