Home / Author Archives: Awoyemi Bamimore (page 43)

Author Archives: Awoyemi Bamimore

Mi ò ní dá DMs lóhùn mó – Davido so béè léyìn ìgbà tí ìkan nínú àwon olólùfé rè pa iró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò.

Ògá àkójopò HKN, Davido, tí ó pe ìkan lára àwon olólùfé rè obìnrin jáde, Sheilah Parker, tí ó gbe lo sí orí èro ayélujàra (snapchat ) láti p’aró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò pèlú arabìnrin náà. Olórin ...

Read More »

Odómokùnrin odún mókàndílógún (19years) tí ósì jí olóyè kan gbé ni owó tè ní ìpínlè River.

Àwon òlùgbógunti Adigunjalè ti ìpín Okehi ní ìpínlè River ni owó won te òdómokùnrin kan tí ó ń jé Emeka Nwala tí ó jé odún méèdógbòn (25years) àti òdómokùnrin Otamasiri Onyesu tí ó jé odún mókàndílógún. Tí won sì fi ...

Read More »

Àwòrán tuntun tokotayà tí won sèsè fé ara won léyìn tí won ti wà gégé bí Òré tímótímó.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó olùgbá bóòlù aláwòn ní Brooklyn, Quincy Acy àti àfésónà rè, Jessica Fuenten tí ó sèsè gbòde kan léyìn ìgbà tí inú arewà ìyàwó àfésónà sì ń dùn, so wípé àwon bèrè gégé bíi ...

Read More »

Odómokùnrin ilé-èkó girama ya Òrébìnrin rè lénu nípa èbùn ojó-ìbí tí ó fun tí ó sì fi gba ìfenukonu.

Àwòrán yí tí Òrékùnrin àti Òrébìnrin ilé-èkó girama ní bi tí won ti ń fi enu ko ara won lénu kárakára tí ó sì ti gbòde kan. Níbi àwòrán yìí arí àwon akékòó nísìírí sí omokùnrin náà bí ó se ...

Read More »

Aláìsàn kan kú látàrí ìdádúró láti owó àwon Dókítà tí ó da isé sílè ní ìpínlè Imo.

Arákùnrin kan tí a dá mò sí Ogbonna Otu tí ìnagije rè ńjé OJB, ti gbé èmí mì nígbà tí ó kérora orí fífó tí ó l’ágbára. Gégé bí Òré olóògbé se so, a yára gbé okùnrin yí dìgbàdìgbà lo ...

Read More »

Àwon olùdáàbòbò pa àwon omo egbé ikò agbésùmòmí Boko Haram nígbà tí won d’ènà dè wón ní Borno. Àwòrán.

Òsùbà fún Civilian Joint Task Force (JTF) ní Gubio ìlú kan ní Borno tí won d’ènà tí won sì pa méta lára àwon ikò agbésùmòmí Boko Haram nígbà tí isé ń gbòde lówó. Àwon olùdáàbòbò gba ìbon àti òkadà padà ...

Read More »