Home / News From Nigeria / Breaking News / Odómokùnrin ilé-èkó girama ya Òrébìnrin rè lénu nípa èbùn ojó-ìbí tí ó fun tí ó sì fi gba ìfenukonu.

Odómokùnrin ilé-èkó girama ya Òrébìnrin rè lénu nípa èbùn ojó-ìbí tí ó fun tí ó sì fi gba ìfenukonu.

Àwòrán yí tí Òrékùnrin àti Òrébìnrin ilé-èkó girama ní bi tí won ti ń fi enu ko ara won lénu kárakára tí ó sì ti gbòde kan. Níbi àwòrán yìí arí àwon akékòó nísìírí sí omokùnrin náà bí ó se gbé èbùn ojó-ìbí náà fún olólùfé rè. Níbèrè Pèpè, ojú kókó ń ti omobìnrin náà sùgbón léyìn ìsírí tí àwon Òré rè fun, ó fa okùnrin náà móra ósì fi enu kò ó lénu.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

masoyinbo

#Masoyinbo Episode Sixty-Four with #Lisabi: Exciting Game Show Teaching Yoruba language and Culture.