Home / Author Archives: Awoyemi Bamimore (page 41)

Author Archives: Awoyemi Bamimore

Àwòrán Afárá(Bridge)tí ó já tí won sì ti kò sílè ní ìlú Ilorin .

      Afárá (Bridge ) yí ni òjò ti gbá dànù láti bí osù díè séyìn látàrí òjò nlá tí ó rò tí àwon ìjoba kò sì se nkankan si . ònà alágbàdo ni afárá yí wà . Nígbà ...

Read More »

Àwòrán ìsìnkú Tagbo Umueke ní ìpínlè Anambra .

      Òré Davido, tí ó n jé Tagbo Ifeatuchukwu Umueike ni ó sùn re ní ogún’jó osù kèwá odún, 2017 (20/10/2017) ní ìlú tí a bi sí. Ní ìjoba ìbílè Osumenyi ní ìpínlè Anambra .    Àwon òré ...

Read More »

Òdómobìnrin odún mókàndínlógún pín àwòràn ilé tí ó rewà tí sugar daddy rè rà fun .

      Òdómobìnrin odún mókàndínlógún tí ó tún jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) ti gba àwon òdóbìnrin ní ìmòràn wípé kí won múra sísé kí won sì gbàgbó nípa èróngbà olórun sí won nígbà tí ó n ...

Read More »

Òdómokùnrin kan ní orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè látàrí wípé àwon ebí rè kò gbà kí ó fé ìyá omo rè .

            Òdómokùrin kan ni orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè léyìn ojó díè tí ó pín nípa àwon ebí rè tí kò gbà fun kí ó fé ìyá omo rè….

Read More »

Nneoma Nkechi àti Rochas Okorocha pín àwòrán won tí ó ti pé .

       E wo àwòrán tipétipé Gómìnà Rochas Okorocha àti ìyàwó rè tí ó rewà, Nneoma Nkechi Rochas Okorocha. Àgbà wá búra bí èwe ò bá se ó rí…

Read More »

Àwòrán ìgbéyàwó ògbóntarigì olórin afòròdárà tí orúko rè n jé Gucci mane .

      Àfòròdárà (Rapper) Gucci Mane àti Keyshia Ka’oir se ìgbéyàwó alárinrin tí ó jé wípé ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won wò ó n’ílé l’óko lórí èro amóhùnmáwòrán.igbéyàwó náà rinlè gan tí ó fi jé wípé àwon ènìyàn jàkànjàkàn ...

Read More »

Omoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti jí bisikitì .

       Ònlò èro ayélujárá ( Facebook) tí a mò sí Arc Pashal Chike Umeobi ló so wípé arábìnrin yí ni owó àwon figilanté tè ní Ezinifite , ìlú kan ní ìpínlè Anambra . Arábìnrin yí ni won fi ...

Read More »

Omokùnrin Wizkid , Ayo kékeré òun àti ìyá rè múra jáde nínú aso orílé èdè Nàíjíríà .

    Binta Diallo àti omokùrin rè ,king Ayo kékeré jáde lo láìpé tí won sì tàn gan nínú Dashiki won àti aso orílè èdè Nàíjíríà. Aso orílè èdè Nàíjíríà yí jé kí ó dà bi omo Yorùbá tí ó ...

Read More »

Nígbà tí adékódère bá padà s’ábúlé .

 Òpò omoge òde-ìwòyé ni a bí sí abúlé sùgbón bí won bá ti jáde díè ìwà àti ìsesí won yóò y’àtò, won á sì gbàgbé orísun won.                           ...

Read More »

Ejò tí mo pa nínú ilé Adìe mi lóòní.

Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí ...

Read More »