Egbe ofo Toko coronal wo Nigeria Egbe abamo ti ki tele ofin. Akuse egbe tin pin rice agolo Kan fun eniyan mewa
Read More »
ayangalu Comments Off on Ewi Toni: Egbe APC iba oooo
Egbe ofo Toko coronal wo Nigeria Egbe abamo ti ki tele ofin. Akuse egbe tin pin rice agolo Kan fun eniyan mewa
Read More »Look for this book: IFA, A COMPLETE DIVINATION by Ayo Salami. It is excellent.
Read More »ayangalu Comments Off on Oodua Fantasy: Creatures from The Forest of No Return:
Kurekure (Ghomid) observing a (Yinmiyinmi) Dung Beetle Adeboye Adegbenro
Read More »ayangalu Comments Off on Ṣeyi Makinde, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Sọ̀rọ̀ Lórí Àrùn Coronavirus Tó Ní
Ìròyìn tó bá ọ̀pọ̀ lẹ́jafùú ni ìròyìn ‘Mo ti ní àrùn Coronavirus’ èyí tí Gómìnà Ṣèyí Mákindé gbé jáde ní ọjọ́ Ajé lójú òpó twitter rẹ̀. Níbáyìí tí ó ti lo ọjọ́ méjì ní ìgbélé lẹ́yìn ìkéde yìí, gómìnà ìpínlẹ̀ ...
Read More »À fi kí Ọlọ́run gbani lọ́wọ́ ẹni tó ń ṣọ́ni tá ò ṣọ́ o, ló dífá fún kójú má ríbi,gbogbo ara lòògùn rẹ̀, bí gbajúgbajà olórin wákà, Salawa Abẹni ti sọ pé, òun ti fi ẹjọ́ abani lórúkọ je tó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus
Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirusÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Ni ipinle Eko ni ori ti ko ogun eniyan yo ni ile iwosan ti won ti n toju awon ti kokoro Covid-19 n ba ja. Bi o tile je pe ...
Read More »ayangalu Comments Off on Adarí àgbà ilé ìwòsàn UCH kò ní àrùn Coronavirus mọ́
Họ́wùú! bí babaláwo bá ń kígbe ẹ̀fọ́rí, kín ni yóó jẹ́ àtubọtán aláìsàn? Kò jẹ́ jẹ́ bẹ́ẹ̀. Adarí àgbà ilé ìwòsàn ẹ̀kọ́ṣẹ́, UCH Íbàdàn Ọ̀jọ̀gbọ́n Abiodun Otegbayo ti yiijẹ o, kò ní àrùn Coronavirus mọ́ lẹ́yìn tó sàyẹ̀wò àrùn náà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà
Orisiirisii awon agbejoro ati awon amofin pelu ojogbon lorisiirisii ni won ti n yo suti ete si igbese awon ijoba orileede yii, paapaa julo lori arun coronavirus to gbode. Won ni ko tile tona rara ki ijoba apapo dede kede ...
Read More »ayangalu Comments Off on Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19
Oni ogbon ojo, osu keta ni ayewo gomina ipinle Oyo, Alagba Seyi Makinde jade, ti ayewo naa si gbee pe o ni arun naa. Oun ni o maa je eleeketa gomina ni orileede yii ti ayewo fihan pe won ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’Ekoo
Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’EkooÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Alaisan marun-un ninu awon ti arun buruku covid-19 ti n ba finra lati bii ose meloo kan seyin gba idande. Yoruba bo “won ni alaare ko ki n ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more