Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m Ariwo t’íjọba àpapọ̀ Nàìjíríà ń pa lé àwọn tó jẹ ẹ́ ni gbèsè owó iná nìyí báyìí o. Ṣùgbọ́n lọ́tẹ̀ yìí kìí ṣe àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè ...
Read More »Ó di láyéláyé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè
Ó di láéláé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè Gbajúgbajà òṣèré Samuel Akinpẹlu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àlàbí Yellow ti jẹ́ Ẹlẹ́dàá nípè. Akọni tí à ń perí yìí jẹ́ òṣèré tí àwọn èèyàn kò ...
Read More »Éèpà Òòsà: Òòsa éèpà
Today is Monday, Ojó Ajé(day of expectation of money), OBATALA DAY.Yorubas would say, “Àrà ňbádá owó ni ò jé” meaning, “I could perform wonders if not for unavailability of money” Never give up trying to have good life. With Obatala, ...
Read More »Àlùfá tọ́ bá ọmọ ọdún méje sùn, wẹ̀wọ̀n ọdún Márùn- ún ní ìpínlẹ̀ Ekiti
Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n t’olóhun.Ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti tífìtàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe jẹ́ ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ láti máa dárúkọ ọ̀daràn afipá bánilòpọ̀ hàn àti láti máa dójú tì wọ́n. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Kayode Fayemi gbé ...
Read More »Ìdí tí a fi yọ Donald Trump nípò Ààrẹ
Alágbára ayé,alágbára ayé,a sè a ṣẹ̀ má lù kan, Ọlọ́run o tíì da sí dúníyàn .Bí nǹkan se n lọ yìí, Donald Trump ni Ààrẹ orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà kẹta nínú ìtàn tí ọ̀bẹ yóó bá ń dìí láti ọ̀dọ̀ àwọn Ilé ...
Read More »Kò sí ilé tàbí só̩ò̩bù tí a kò le fo̩ láti ké̩rù òfin – Àjo̩ Customs
Awon ajo asobode ile Nigeria ti gbogbo eniyan mo si Customs ni won n ba awon oniroyin soro ni ipinle Adamawa pe, ko si ile tabi soobu ti awon ko le ja tabi fo ti o ba ye.Won ni gbogbo ...
Read More »Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’Ekiti
Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’EkitiYinka AlabiIdaji oni ojo kokanlelogun, osu kejila odun yii ni awon ara ilu Orin Ekiti dede de oko ti won ba Asia pupa to tumo si wi pe, ki awon ara agbegbe naa ma se ...
Read More »Odu Ifa: “Irente gbe” cast for today’s Ose Ifa
Looking at the Odu, “Irente gbe” cast for today’s Ose Ifa, it is revealed that sometimes you sit down on the mat instead of kneeling down for supplication to Ifa. Just listen as follows:- Àyàn Awo Oníjan lódífá fún OníjanNíjó ...
Read More »Ilé Ẹjọ́ Tó Ga Jù Dá Seyi Makinde Láre Gẹ́gẹ́ Bíi Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Ilé ẹjọ́ tó ga jù dá Seyi Makinde láre gẹ́gẹ́ bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀rọ̀ Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lọ́wọ́-lọ́wọ́ onímọ ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé tí di ọmọ oṣupa lé ẹ̀ ní kò gún,……bí Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ lórílẹ̀-èdè ...
Read More »Àkòdì Òrìṣà
Ifa is the past, present and the future Ifa is timeless Because time is part of Ifa,
Read More »