Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).
Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè ...
Read More »ayangalu Comments Off on Between Alaafin & Elders Of Yoruba Religion Over Oba Ifa Adimula Of S. America Title
Elders of Traditional Religion worshipers under the aegis of the Concerned Committee of Yoruba Traditional Culture and Faith Ambassadors have stood in defence of three Ifa priests accused of impersonating the Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, and extorting some ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.
Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè Obafemi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjoba ìpínlè Èkó dá àwon òsìsé KAI dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won.
Ìjoba ìpínlè Èkó, lábé àse Gómìnà, láti jé kí ìlosíwájú bá ètò ìlera ti dá àwon òsìsé KAI (kick against indiscipline) dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won. Ìgbésè náà, gégé bí ìjoba ìpínlè náà, jé òkan lára ìsàkóso ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àyàngbàjù! Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Evans pe ògá olóòpá l’éjó,
**Àti Àwon Méta Míràn Látàrí Àtìmólé Rè Ní Gbogbo Ìgbà. Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Chukwudumeme Onuwuamadike tí ìnagije rè ńjé Evans, ó ti pe ògá olóòpá l’éjó, tí orúko rè ńjé Ibrahim Idris àti àwon méta míràn ní ilé ejó gíga ti ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oko mi fi mí sílè nítorí pé mi ò tí bímo. Okàn mi ń pòrúrú… Egbàmí!.
…Mi ò ti è mo bí mo se fé bèrè. Ó dàbí kí ń parí gbogbo rè. Oko mi sèsè fi mí sílè torí mi ò tíì bímo àti wípé kò fé kí won gba àtò rè àti eyin mi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwòrán ilé-ìwòsàn Giginju àti irinsé orísirísi ti ilè Kano tí ó jé bílíònù lónà méji àti egbèrin néírà (₦2.8 billion)
Gómìnà ìjoba ìpínlè Kano ti ra irinsé ńlá fún ilé-ìwòsàn Giginju rè tí ó sèsè kó tán ní ìpínlè Ìjoba náà. Àwon irinsé náà ni 1.5Telsa Magnet Resonance Imaging, MRI machine, tí ó rà ní owó tí ó tó mílíònù ...
Read More »ayangalu Comments Off on Arákùnrin kan se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Èkó.
Arákùnrin kan ní orílè èdè Nàìjíríà tí a mò sí Jefferson Uwoghiren, se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Edo. Arákùnrin náà tí kò so ohun tí ó fé fi eranko afayàfà náà se, ni ...
Read More »Gégé bí akékòó tí kò ti parí ní ilé-ìwé gíga ifáfitì, àsìkò kan wà tí a ó rò wípé ayé ti ń se wá, àsìkò kan sì wà tí a ó rò wípé a ga ju ayé lo. Ohun tí ...
Read More »ayangalu Comments Off on Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi.
Gégé bí ìròyìn se so, Gómìnà ìpínlè Kogi: Yahaya Bello ri èro amúnáwà tí agbára rè tó Egbèédógún (300KVA) ní òpópónà kan ní Lokoja gégé bí isé rè àkókó léyìn tí ó ti lo odún kan àti ààbò lórí ipò. ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more