Home / Art / Àṣà Oòduà (page 171)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Kilofa ti ikun arakunrin yii figa bayi

Read More »

Nje E Ranti Aworan Yii???

Read More »

Kin Ni Oruko Baba yii

Read More »

kini yoruba mape oruko kini yi

Read More »

Eyin Eyan mi Tani eyin ma di IBO yin fun ninu a won mejeji.

Eyin Eyan mi Tani eyin ma di IBO yin fun ninu a won mejeji. Jonathan tabi buhari

Read More »

Ẹ ma b’Ogun fija ṣere, ara Ogun kan go go go

[KGVID width=”640″ height=”358″ downloadlink=”true”]https://ooduarere.com/wp-content/uploads/2014/11/ogun.mp4[/KGVID] An Epic Oriki of Ogun

Read More »

E je kawa imo ku imo Ewo lo to na ninu awon oro won yi

1) Ki lori lobe to fi wa iru so wo  2) ki lori lobe to fi waru owo  3) ki lori to fi garu owo  4) ki lori lobe to fi wa owo ru 5) ki lori lobe to fi ...

Read More »

Kinni eyin npe ladugbo yin

Wonwo re lede wa legbado kinni eyin npe ladugbo yin ,obe re ninu ata dindin

Read More »

Gbolohun kan fun

E dakun e ba mi wi Gbolohun kan fun

Read More »

Ọ̀RỌ̀ ÌSÍTÍ

Húùm…ètò ìsèlú tiwa-ntiwa kò yẹkí ó mú ìjà wá bí ó bá se wípé l’òtítọ́ la n’ìfẹ́ ará ìlú l’ọ́kàn, k’ára ó leè dẹ t’ẹrú-t’ọmọ yàtọ̀ sí ìsèlú bí-o-ba-o-pá, bí-o-kò-báa-kó- bu- bùú-l’ẹ́sẹ̀, èyí tó wọ́pọ̀ l’órílẹ̀ èdè wa!!. Àwa ọmọ ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb