N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀dá ò láròpin láyé, ṣé bí ó se wu Olúwa Ọba níí sọlá, fẹ́ni Ó wù ú,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ níbi tí t’ọba, tìjòyè, ọ̀tọ̀kùlú ìlú ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele
N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀dá ò láròpin láyé, ṣé bí ó se wu Olúwa Ọba níí sọlá, fẹ́ni Ó wù ú,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ níbi tí t’ọba, tìjòyè, ọ̀tọ̀kùlú ìlú ...
Read More »ayangalu Comments Off on Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu
Ogbeni Babajide Sanwo-olu ni mi. Mi o ki n n se “His excellency”.Gomina ipinle Eko lo n salaye yii fun awon oniroyin lonii ojo kefa osu kokanla odun yii.Gomina ni igberaga wa ninu oruko ” His Excellency “. E saa ...
Read More »ayangalu Comments Off on A Dúró Lójú Òpó Ìdájọ́ Ilé Ẹjọ́ Àkọ́kọ́ Lórí Ẹjọ́ Ajimobi – Adájọ́
A dúró lójú òpó ìdájọ́ ilé Ẹjọ́ àkọ́kọ́ lórí ẹjọ́ Ajimobi – Adájọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà àná ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Abiola Ajimọbi ti fìdí rẹmi nínú ìpẹ̀jọ́ rẹ̀ láti tako ìbò tí ó gbé ojúgbà rẹ̀ Kọla Balogun wọlé gẹ́gẹ́ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àṣírí Pásìtọ̀ Tó Ń Fí Sọ́ọ̀si Ṣe Ọ̀gbà Wèrè Tú
Àṣírí pásìtọ̀ tó ń fí sọ́ọ̀si ṣe ọ̀gbà wèrè tú Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé biribiri òkuǹkùn ọ̀rọ̀ lójú ọmọ aádámọ̀ ,ìmọ̀lẹ̀ gbòò ni lójú Adẹ́dàá. Ní báyìí, Olùsọ́ àgùtàn Joseph Ojo, ní ọwọ ṣìnkún ọlọpàá ti mú fún lílo ilé ìjọsìn ...
Read More »Iroyin asise nomba moto asofin ilu Kano, Ogbeni Ayuba Durum ran kaakiri bi ina inu oye, paapaa julo lori ero ayelujara. Eyi wa ya gbogbo aye lenu pe se bee ni awon ajo FRSC tii se adari eto irinna ati ...
Read More »ayangalu Comments Off on Lai Mohammed fa o̩mo̩ Naijiria létí lórí ìròyìn òfegè
Lai Mohammed fa ọmọ Nàìjíríà létí lórí ìròyìn òfegè Fẹ́mi Akínṣọlá Mínísítà ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìròyìn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Lai Mohammed ti ní ìjọba yóò bẹ̀rẹ̀ ṣí í ṣe àmójútó àtagbà ojú òpó ayélujára báyìí.Ìgbésẹ̀ yìí ni láti ṣe àfọ̀mọ́ ojú ...
Read More »ayangalu Comments Off on Vietnamni , ẹ wá dá oko ìrẹsì sílẹ̀ ní Nàíjíríà, dípò kíkórẹsì wọlé– Oshiomole fèsì ẹ̀bẹ̀
Vietnamni , ẹ wá dá oko ìrẹsì sílẹ̀ ní Nàíjíríà, dípò kíkórẹsì wọlé– Oshiomole fèsì ẹ̀bẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Bí Ìjọba Nàíjíríà se gbé àwọn ẹnu ọ̀nà àbáwọlé sí orílẹ̀ -èdè yìí tìpa ti ń mú kí orí ta àwọn lórílẹ̀-èdè ...
Read More »ayangalu Comments Off on Atiku tún pàdánu nílé e̩jó̩ tó ga jù
Atijo tun padanu nile ejo to ga juLati owoYinka AlabiIle-ejo to ga ju lo ni orileede yii ti se idajo lori ejo ti oludije dupo Aare ni abe egbe oselu PDP, Alhaji Atiku Abubakar.Ile-ejo ni Aare Muhammadu Buhari naa ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Èmi kò fé̩ràn láti máa fe̩nu ko obìnrin lé̩nu nínú eré – Taiwo Hassan
Taiwo Hassan Ọlọ́jọ́ọ̀bí, akọni òṣèré Yollywood tó dáńtọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Yoòbá bọ̀, wọ́n ní èèyàn tó bá monú-ún rò, ọpẹ́ ẹ rẹ̀ yóó lékún bóyá n ló fa sábàbí bí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ọmọ Nàìjíríà ti ń darapọ̀ kí àgbà òṣèré Taiwo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Akpabio fajúro sí owó ìnákúùná Niger Delta
Akpabio fajuro si owo inakuna Niger DeltaLati owoYinka AlabiIjoba apapo ti Senato Akpabio n soju fun lo ti gbanaje lori awon ise ajanbaku to n waye ni agbegbe Niger Delta. Akpabio ni o ye ki ise ijoba maa te siwaju ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more