Home / Art / Àṣà Oòduà (page 42)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Ooni ti Ilè- ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi Enitan ti setán láti fé Tope Adesegun gégé bí olorì tuntun.

oni ti ilè-ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi tí òun àti olorì télè èyí tí a mò sí olorì Wuraola tí pínyà ní osú ògún tí a mò sí odù kejo odún 2017, nse ni ó dàbí baba ti rí olólùfé ...

Read More »

Arákùnrin tí ó jé omo Ebonyi, ìpínlè kan ní orílè èdè Nìjíríà yí ti kú sí ilè Italy pélù àwon mókànlá míràn.

Èyí bani ní inú jé púpò, arákùnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà yí ti kú pèlú àwon mókànlà míràn ní inú ìjàmbá okò tí ó selè ní Foggia ní ilè Italy. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé yí, ...

Read More »

Omobìnrin kékeré yí ni won dáné sun nígbà tí won fi èsùn kàn án wípé àjé ni, ní ìpínlè Akwa Ibom.

Àwòrán tí ó wà ní ìsàlé yí ni àwòrán omobìnrin kan tí orúko rè a máa jé Queen, won dáné sun omo yí látàrí èsún tí won fi kàn án wípé Àjé ni. Anja Louvre tí ó jé panépané ní ...

Read More »

Àràbà Aworeni Adisa Makoranwale sun re.

òní tí ó jé ojó kokànlá osù kejo odún 2018 (11/8/2018) ni ètò ìgbé òkú baba wa tí ó sísè ní ojo ìségun tí ó jé ojó kokànlél’ógbòn osú keje odún tí a wà (31/7/2018) sí isà . Ìjo International ...

Read More »

Timi Dakolo pín àwòrán ti ó rewà ti ìyàwó rè pèlú omo méta ní London.

Gbajúgbajà olórin ti orílè èdè Nìjíríà, Timi Dakolo ti pín àwòrán ìyàwó rè àti àwon omo rè méta ní ìlú London, ó ko síbè wípé “wón tun ti dé baba wón tún ti dé”. Timi Dakolo ti ó jé omo ...

Read More »

Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó kéreké parí ilé-èkó gíga ifáfatì ti ìlú ìbàdàn (university of Ibadan).

Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó, Oba Lamidi Adeyemi kékeré, ti parí ifáfitì ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Ibadan tí a mò sí University of Ibadan. Bí omo bá dára ká so, ó ye kí á yé olorì sí ...

Read More »

Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-Èdè Braṣil: Ẹ Dáàbò bo Ẹ̀sìn Ìbílẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú (Yoruba version by Akin Ogundiran)

Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-Èdè Braṣil: Ẹ Dáàbò bo Ẹ̀sìn Ìbílẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú (Yoruba version by Akin Ogundiran) Àbádòfin kan ti kalẹ̀ ní ìlú Rio Grande do Sul ní ilẹ̀ Braṣil tí yô ká àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ aláwọ̀dúdú lọ́wọ́kò láti máa ...

Read More »

A kú àmójúbà *Oṣù Ògún (August) tuntun.* Oṣù ìdùnnú ni yóò jẹ́ láṣẹ Èdùmàrè

A kú àmójúbà *Oṣù Ògún (August) tuntun.* Oṣù ìdùnnú ni yóò jẹ́ láṣẹ Èdùmàrè. Gbogbo àdáwọ́lé wa ló máa yọrí sí rere. Aboyún ilé á bí wẹ́rẹ́, àgàn á tọwọ́ àlà bọ osùn. Gbogbo ẹni tó ń ṣòwò yó jèrè, ...

Read More »

Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè.

Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè. Olúsèse, Àràbà àgbáyé ti dágbére wípé Ó dígbà fún aráyé, baba ti lo rè é bá àwon baba ńlá rè ní ìwàlè àsà. Ó ...

Read More »

Eka-èkó tí ó ń kó nípa Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò (festival of food and identity).

Ni Àná tí ó jé ogbòn-ojó osù keje odún 2018, ni eka-èkó ìmò àti Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò. Òjògbón Wole Soyinka kò gbéyìn rárá Baba náà péjú pésè níbi odún ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb