Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Oonirisa ni Ilu Oyibo: Abike jagaban, Esabod..
Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìgbà èdá
Ìgbà kò lo bí òréré Ayé kò lo bí òpá ìbon, Ìgbà kan ńlo Ìgbà kan ńbo Kí elédùmarè jé kí á n’ígbà tó dára n’ílé ayé wa Ìgbà kan ni ogún náírà yí níyì púpò Sùgbón nísìnín Ó ti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ahmed Musa ti mu Nìjíríà rérìn-ín ayò léèkan sí.
Gégé bí a ti mò wípé eré bóòlù ife àgbáyé ńlo lówó. Ahmed Musa tí Ó jé òkan Lára àwon omo agbábòòlú Nìjíríà ti gbá bóòlù méjì òtòtò wo ilé àwon alátakò won tí a mò sí ikò Iceland.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òrìsà tí ń darí aféfé
Oya òpèré, Ekùn oko asè’ké Oya má bá mi jà Mi ò l’ówó aféfé ńlé Èmi ò rí eni tí yó ràgàn, ràgàn bí Oya ní òde ìpo Kò séni tí ó ràgàn ràgàn bí Oya lótù ifé Oya lo ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on E wá wo isé tí Àlùbósà.
_Sebí ohun tó bá jọnilójú, ni Yorùbá n sọ wí pé ó yanilẹ́nu. *Àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì kan ní ìlú CHINA ti jẹ́ kó yé wa wí pé ìwádìí tuntun tí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wí pé ÀLÙBỌ́SÀ (kò báà ṣe ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Eniyan koni rajo kofi orire kale sile ibiti aba koriwa mase pada leyinwa oo
Ori mi Apere isedami Ajifobi kan Amuni wale aye magbagbe Eni Orimi gbemi bose gbe omo alara tofidade owo isedami gbemi bosegbe omo ajero tofi tepaleke orimi gbemi bose gbe omo orangun ila tofidi eni apesin pitipiti mogbani Adurafun wape ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Eniyan koni rajo kofi orire kale sile ibiti aba koriwa mase pada leyinwa oo
Ori mi Apere isedami Ajifobi kan Amuni wale aye magbagbe Eni Orimi gbemi bose gbe omo alara tofidade owo isedami gbemi bosegbe omo ajero tofi tepaleke orimi gbemi bose gbe omo orangun ila tofidi eni apesin pitipiti mogbani Adurafun wape ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Odún ifá àgbáyé !
Odù ifá tí ó sòkalè ni *ìretè-ìká* ifá pé ire aya (couples blessing) ifá ní a ó se òpòlopò Odún láyé. Ifá ní kí á rúbo lópòlopò wípé Odún yìí yóò sàn wá fún ajé, aya, Omo, ogbó ató àti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ooni ti ile-ife ní ìdí òpe àgùnká .
Ayeye Odún ifá àgbáyé eléyìí tí ó wáyé ní òkè-ìtase ní ilú ilé-ifè. Ooni rèé ní ìdí òpe àgùnká ní ibi tí mùtúmùwà ti ń se àdúrà sí ìsèdá won, kódà oba náà kò jáfara.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìwúre Òṣù Tuntun
Bí ÒṢÙ bá yọ loke terutọmọ niiri, omi ajipon kiiru, ninu ÒṢÙ kẹfa yi aye gbogbo wa yio toro minimini, bi Ọgẹdẹ ba pọn ará aa dẹẹ, ara oni ni emi àti Ìwọ oluka àtèjìṣẹ mi yi, àtijẹ atimu koni ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more