Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Gbajúgbajà òsèré, Mercy Aigbe pín ìròyìn ìbànújé.
Òsèré, ìyá, àti oní káràkátà ti pín aí orí èro ayélujára láti polongo wípé bàbá òun ti dágbére f’áyé.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Jamil Balogun, omo Tiwa Savage yo pèlú àrà òtò nínú àwòrán tí ó yà.
Omokùnrin Tiwa Savage, Tunji ‘Tee Billz Balogun ti è ti rewà jù. Gbajúgbajà olórin Tiwa Savage pín àwòrán omo rè tí ó rewà, Jamil Balogun nàà yo ní àrà òtò nínú aso aláwò pupa tí ó yí orùn ká.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Buhari ti búra fún Boss Mustapha gégé bíi akòwé ìjoba gbogboogbò (SGF).
Àare Muhammadu Buhari ti se ìbúra fún akòwé ìjoba gbogboogbò tuntun tí ó n jé Boss Mustapha . Ayeye ìbúra náà wáyé ní yàrá ìgbìmò Ààre.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Olópàá tí owó tè nígbà tí ó n gba owó èyin ní ojà Yola.
Gégé bí ò n lò èro ayélujára tí ó gbé ní Yola tí ó pín ìròyìn ìsèlè yí se so, olópàá tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí ní won yà nígbà tí ó n GBA owó èyin ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Terry G se ayeye ojó ìbí fún omokùnrin rè, Teerex nígbà tí ó pé odún márùn-ún.
Omokùnrin Terry G, Teerex pé omo odún Márùn-ún bàbá rè sì se ayeye ojó ìbí náà fun pèlú àwon òrò tí ó dùn tí ó pín sí orí èro ayélujára (Instagram).
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Cossy Orjiakor ní ilé-ìwòsàn tí ó fé se isé abe kí ìdí rè le yo.
Cossy Orjiakor tí a mò wípé óní àyà ni a ti gbó tí ó ti kérora nípa ìdí rè tí ó kéré lénu ojó meta yí, sùbón báyìí ó ti lo sí ilé-ìwòsàn láti sisé abe kí ìdí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìyàwó ga oko kúrú.
Àwòrán àwon tokotaya tuntun, kí olórun fún won ní adùn ìgbéyàwó . Èyí ò wa rewà bí…
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Patoranking lo kí Timaya pèlú okò rè tuntun tí won n pè ní Porsche.
Gégé bí Timaya se pin sí orí èro ayélujára(Instagram) tí ó sì wípé . ” omo mi ti dé pèlú àrà òtò, gbogbo ìgbà ni ó ma n mú orí mi wú. PATORANKING mo féràn re ….
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìlò wèrè aso Okrika (aso tí won ti lò rí).
‘Okrika’ ni ònà tí àwon ènìyàn Nàjíríà n gbà pe aso tí won ti wò rí, tí won sí wo ìlú. Nígbà tí àwon nkan ti sa èyí tí ó dára níbè àwon kan kò ní aso tí won ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more