Orí. Kò sí òòṣà tí í dá ni í gbè lẹ́hìn orí ẹni. Orí là bá bọ, à bá fòrìṣà sílẹ̀. Ori mi gbere ko mi loni o..
Read More »Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀ Ẹnu lẹbọ.
Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀ Ẹnu lẹbọ. Kí là ń bọ nÍfẹ̀? Ẹnu wọ̀n Ẹnu wọn là ń bọ nÍfẹ̀ Ẹnu wọn. Kí ẹnu mi má kó bá mi o Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀ The mouth is an altar of worship. What is it that we worship ...
Read More »Bawo ni ase le ko nipa odu ifa erindinlogun.
Olotu, Bawo ni ase le ko nipa odu ifa erindinlogun.
Read More »Iwure Eyonu Awon Agba
Edumare,Oba Ajiki,Ajige,Oba toto bi aro. Awa dupe lowo re ,pe o yo nu si wa lati atete ko se titi di oni oloni. Jowo Baba Alanu ,masai ko Anu re kuro Lori wa (mi). Jowo Baba ologo lola ,je ki ...
Read More »Tani oma yin logo ti oba ji?
1.Eledumare 2.Mohamedi 3.Jesu 4. Satani Sojunu ti oba ji
Read More »E dakun eba wa fun Ogbeni yi ni oruko kan
Oruko wo leyin npe oko yi ladugbo tiyin ?
laba tia agbegi ma gbeyawo
Read More »Kini Won Npe Iru oko yi ni ede Tire ?
E bami Dasi Oro yi Eyin elegbe mi…
Ninu Obi Eni tabi A’ya Eni, ewo lose pataki ?
Read More »Aje olokun yo fiso sile gbogbo wa ooo
AJÉ Iwọ́nrín Olókun a bi ara á ‘le koko bí ọta, Òhun l’ó d’ifa fún orí Àpéré ọ̀nà ọmọ a t’Àkàrà ṣ’ọlà.. (Ajé brings prosperity. I wish all Ifa University members a prosperous Ifa year. )Aṣẹ.
Read More »