A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn ...
Read More »ayangalu Comments Off on Arewa Toni
ayangalu Comments Off on Oga Bello àti iyalode Binta Mogaji
Awon agba osere apanilerin meji
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.
Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.
E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa. Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, Olorun eledumare yio jeki aje fi ile wa se ibugbe loni o ase. Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE lo gate laaro yi, ifa yi fore aje lopolopo fun akapo ti o ...
Read More »admin Comments Off on Musa Musa, olóòpá tí ó fó ilé Jonathan.
Àwon Agbófinró ti rí àwòrán olóòpá kan tí ó jé atónà fún àwon ìgárá olóshà tí ó fó ilé Ààre télè Goodluck Jonathan ní Gwarimpa Abuja. Musa tí a gbé lo sí ilé-ejó gíga díè (magistrate) ní ojó ìségun tí ...
Read More »admin Comments Off on Omokùnrin kan tí orúko rè ńjé Charlyboy subú lulè nígbà tí won ń se àtakò Buhari.
Àmóhùnmáwòrán Channels ti pín fídíò tí ó se àfihàn omokùnrin kan tí ó ń jé Charlyboy nígbà tí ó subú lulè nígbà tí won ń tako Buhari lówó ní ìlú Abuja láàárò òní. Àwon Agbófinró fín tajútajú àti omi láti tú ...
Read More »admin Comments Off on Òrékùnrin mi ń bínú sími.
E jòwó, mo fé àmòràn lórí ohun tí ó ye kí n se, osù kewàá rèé tí mo ti mo Òrékùnrin mi, a sì ní ìfé ara wa, sùgbón Òrébìnrin rè télè sì ń dàá láàmú, èyí sì ń jé ...
Read More »admin Comments Off on Eré odún Òrìshà ní orílè èdè UK Edinburgh Fringe.
Àwon Òrìshà, Yemoja, Oya, Òshun, Elégba àti òshóòsì jé àwon Òrìshà tí ó dúró fún èdá ènìyàn ní gbogbo ònà, tí won sì máa ń wá sí ayé gbangba. Nígbà tí akoni wa òshóòsì, tí ó jé ògbójú ode, tí ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more