Láàrin ogún-l’ógbòn àwon akékòó tí ó tó 1,559,162 tí won jòkó fún ìdánwò àsekágbá ilé -èkó girama tí a mò sí waec ní odún 2017 tí ó jé wípé òpò ni a ti rí, tí ó sì dára … Akékòó ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Èsì ìdánwò alásekágbá ilé-èkó girama (waec)tí ó burúkú jù nínú odún 2017, tí a rí he.
Láàrin ogún-l’ógbòn àwon akékòó tí ó tó 1,559,162 tí won jòkó fún ìdánwò àsekágbá ilé -èkó girama tí a mò sí waec ní odún 2017 tí ó jé wípé òpò ni a ti rí, tí ó sì dára … Akékòó ...
Read More »admin Comments Off on Ìbon ba àwon ajínigbé nígbà tí won ń dúnà pàsípààrò lówó ní ìjoba ìpínlè Abia.
Àwon ajínigbé mérin, èyí tí won ti ń da ìpínlè Abia àti agbègbè rè láàmú. Won ti ń gbìyànjú àti parun tí àwon òtelèmúyé so mó Omoba Division ní ojó ketàdínlógún osù keje (19th July ,2017) ní Ovungwu, Isiala -Ngwa ...
Read More »admin Comments Off on Ònà tí èèyàn le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin. (Ways To Deal With An Introverted Wife)
Tí ènìyàn bá wà lábé òrùlé kan náà, ó ye kí won kókó gbà pé ìwà wa kò le b’ára wa mu. Nígbà kan náà o kò ní láti yí enìkejì padà kí o sì jé oníyè ara re. Kódà ...
Read More »admin Comments Off on Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje àjòdún Washington DC jollof.
Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigeria jollof rice) ti kéde gégé bi ipò àkókó nínú ìdíje àjòdún Washington DC jollof. Ní ojó kejì osù keje odún 2017(july 2, 2017) omidan Atinuke Ogunsalu ti Queensway Restaurant &catering in Maryland US, ti se ipò ...
Read More »admin Comments Off on Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task force) nígbà tí owó bà wón ní Benue.
Òdómokùnrin méta kan ni owó àwon civilian Joint Task Force Nígbà tí won jalè lówó ní Jato Aka ní ìpínlè Benue tí won pa wón ní bíi agogo méjì òwúrò òní (2am). Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè náà, ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ta Ni Elújoba?
Elújoba ni gíwa tí ó kúrò Lóríi oyè gégé bíi alásé oau Láìpé yìí Tí gbogbo ènìyàn sì n kan sárá sí òjògbòn náà kìí kúkú se pé wón n déédé kan sáárá sí Baba Ìwà rere àti òótó inú ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwon òrìsà tí e kò mò (sùgbón tí ó ye kí á mò) {Some Orisa you probably don’t know (But you have to)}
Òrìsà Bayani. Òrìsà alágbára yí ni òrìsà omodé tí a bí pèlú dàda . Ó dára kí a ma bo òrìsà yí kí á sì ma bèèrè fún ìdábòbò, kí á b’orí òtá àti gbogbo ire ilé ayé. Gbogbo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àsírí sèsè tú sí won lówó wípé ilé-isé mi ní iye owó tí ó tó Dólà lónà ogóòrun Mílíònù ($100 million) -D’banj.
Kokomaster tí a tún mò sí D’banj le sèsè di òsèré tí ó lówó jù ní ilè adúláwò (Africa). Olórin tí ó sì jé baba omo kan sèsè gbe sí orí èro ayélujàra (instagram) rè pé Cream platform tí ó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Gáàsì bú gbàmù ní Cross river tí ó sì pa èèyàn méji, tí ó fa ìpalára fún àwon mérin nínú ebí.
Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú gbàmù láti ...
Read More »ayangalu Comments Off on Yakubu Gowon lo kí Shehu Shagari.
Olórí ìpínlè télè (former head of state) General Yakubu Gowon lo kí Ààre ti télè Shehu Shagari ní ilé rè ní Sokoto. Gómìnà Tambuwal sìn-ín lo pèlú Olórí àlùfáà Ìjo Catholic ti Sokoto, Bishop Matthew Hassan kukan àti àwon ènìyàn ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more