Oro to panilerin ninu itakuroso ti o wa laarin arakunrin yi ati ololufe re tele eyi ti o yan je. Arakunrin naa kunle lati beere owo owo arabinrin orobo yi fun igbeyawo.. Eyi ni lati fi ife otito han si ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Odomokunrin Kan Ni Orile Ede Naijiria Ati Ara Binrin Oyinbo To Sanra Mu Ki Awon Eniyan Soro
Oro to panilerin ninu itakuroso ti o wa laarin arakunrin yi ati ololufe re tele eyi ti o yan je. Arakunrin naa kunle lati beere owo owo arabinrin orobo yi fun igbeyawo.. Eyi ni lati fi ife otito han si ...
Read More »ayangalu Comments Off on Sangbafo! Won Ge Apa Ati Ori Arakunrin Kan Nitori Ija Ile Ni Ipinle Delta
Ajalu ti o n sele lowo ni amai ati umuebu ni agbegbe iwo oorun ni ijoba ibile ndokwa ti owa ni ipinle delta – o ti gba ona iburu nipa pipa odomokunrin kan ti won ge apa ati ori re ...
Read More »Lolade Comments Off on Aawọ ni Oshodi: Oluomo, Talonskibo, Harmburger Ati Oluwo.
English Version Continue after the page break
Read More »ayangalu Comments Off on Ìpínlẹ̀ Èkó ṣe Àjọyọ̀ Ìdásílẹ̀ Àádọ́ta Ọdún
Ìjọba-àpapọ̀ sọ Èkó di ìpínlẹ̀ ni àádọ́ta ọdún sẹhin. Èkó jẹ́ olú ilú fún gbogbo orilẹ̀ èdè Nigeria tẹ́lẹ̀ ki wọn tó gbe lọ si Abuja. Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ ikan ninú ipinle mẹ́fà Yorùbá. Yorùbá ni “Èkó gba olè, ó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àpẹrẹ Ìsìnkú Ìbílẹ̀ fún Arúgbó ni Ilẹ́ Yorùbá
Ìnáwó rẹpẹtẹ ni ìsìnkú arúgbó jẹ́ ni ilé Yorùbá. Bi arúgbó bá kú ni ilé Yorùbá ki ṣe òkú ọ̀fọ̀ ṣùgbọ́n òkú ijọ àti ji jẹ, mi mu ni pàtàki bi irú arúgbó bá bi àwọn ọmọ ti ó ti ...
Read More »Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? aku ijosin ifa toni to je ojo abameta, Olodumare ninu aanu re koni da emin wa legbodo lati le se pupo ijosin naa loke erupe o Ase. Idanileko ti aaro yi jade lati inu ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọọ̀ni Kò Ṣe Rífín ! (Apá Kìíní Lati Ọwọ́ Daniel Adefare)
Oríadé, ọrùn-ìlẹ̀kẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ajunilọ mo júbà o. Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní “Kíkéré labẹ́rẹ́ kéré, kìí ṣe mímì fádìyẹ” Káláyé tó dáyé, kékeré kọ́ ni Bàbá fi ju ọmọ lọ. Ọọ̀ni kìí ṣe ẹgbẹ́ ọba kọ́ba gẹ́gẹ́ ìtàn ti ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure ojo ajé toni jade ninu odu mimo ogbe onigun.
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi ana o, Olodumare yio funwa nisinmi o, bi oni se je ojo ajé ao raje sokun ao raje sede ao si raje saiku baale orò o Ase. Iwure ojo ajé toni jade ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oríkì Àjọbí, Àṣà Yorùbá ti ó Nparẹ́ lọ
Oríkì* jẹ ọ̀rọ̀ ìwúrí ti Yorùbá ma nlò lati fi sọ ìtàn àṣà àti ìṣe ìdílé lati ìran dé ìran. Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i ...
Read More »ayangalu Comments Off on Olopa pa obirin kan ni ilu Eko
Olopa yinbon pa iyawo ile kan , ni adugbo kan ti aun pe ni Onipanu ni ilu Eko, nigba ti oun le ikan ninu awon omo ti won ma un fi ero ayelujara jale. Awon agbofinro so wipe won yi ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more