Ìlẹ̀ Amẹ́ríkà mà ti gba ipò kínní gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè tí ìtànkálẹ̀ Coronavirus ti pọ̀jù lọ l’ágbàáyé pẹ̀lú ènìyàn tó lé ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà márùndínláádọ́rún tó ti ní àrùn náà.
Read More »Ojúmọ́ Kan, Oògùn Kan
Ilu nla bii orileede Naijiria sowon lagbaye. Ko si odun kan tabi osu kan to le lo lofee ki o ma se si ohun kan ti a maa gbe poori enu. Igba miiran, o le je Obasanjo lo maa ko ...
Read More »Sanwo-olu Máa Fún Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Igba Ènìyàn Lóúnjẹ L’eko
Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan ...
Read More »Ariwo kí ló ń ṣẹlẹ̀ ní Akure ní àwọn ènìyàn fi bọnu!
Ó kéré tán Ilé méjì tí àwọn ènìyàn ń gbé, ilé ẹkọ ati Ilé ìjọsìn ló wó ní ìlú Akure lẹ́yìn tí ìbúgbàmù dún ní ìpínlẹ̀ Ondo.
Read More »Manchester United Ti Se Tán Láti Ra Odion Ighalo Pátápátá
Manchester united ti se tán láti ra Odion Ighalo pátápátá Lati owo Akinwale Taophic Se won ni ti egungun eni ba jo re, ori a ma ya atokun re. Ati wi pe, Ku ise ni n mu ori eni ya! ...
Read More »Ronaldinho Ń Kó̩ Is̩é̩ Gbé̩nàgbe̩nà Nínú È̩wò̩n Ní Orílèèdè Paraguay
Ogbontarigi ninu boolu alafesegba to je omo bibi orileede Brazil ti o si ti fi igbakan ri je eni akoko ninu boolu alafesegba kaakiri agbaye, Ronaldinho,
Read More »Àfàìmọ̀ Kí Coronavirus Má Dà Bí I Ti China Tabi Italy- Mínísítà Kìlọ̀
Ẹni mẹ́rin mì ìn kó àrùn apinni ní mímí èèmii coronavirus ní Nàìjíríà,àfàmọ̀ kò mọ́ dà bí i ti China,l Italy— Mínísítà kìlọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ìgbọrọ̀ sàn ju ẹbọ rúrú fún ẹni tó bá fẹ́ gbọ́ ni o.Ó ti di ...
Read More »E̩ Fi Àdúrà Rànmí Lọ́wọ́, Nítorí Ọmọkùnrin Mi Ti Lùgbàdi Àrùn Coronavirus … Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀ Yìí Nígbà Kan
Ẹ fi àdúrà rànmí lọ́wọ́, nítorí ọmọkùnrin mi ti lùgbàdi àrùn coronavirus … igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀ yìí nígbà kan
Read More »Àwọn Fíìmù Òde Òní Ń Kọ́mọ Lólè Àti Ọ̀pọ̀ Ìwà Burúkú – Iyabo Ogunsola
Àwọn fíìmù òde òní ń kọ́mọ lólè àti ọ̀pọ̀ ìwà burúkú Fẹ́mi AkínṣọláṢé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní ẹgbẹ́ burúkú ba ìwà rere jẹ́. Ajíyìnrere Felicia Iyabode Ogunsola tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Efúnsetán Aníwúrà, Ìyálọ́de ìlú Ìbàdàn nínú eré, ...
Read More »Ènìyàn O̩gbò̩n Ti Lùgbàdì Coronavirus Ni Naijiria
Ènìyàn o̩gbò̩n ti lùgbàdì coronavirus ni NaijiriaÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Afi ki Eledua maa ko wa yo ni orileede yii. Bi ere bi awada, ajakale arun kogboogun (covid-19) ti mu eniyan ogbon di asiko ti a n ko iroyin ...
Read More »