Àwon omo egbé òkùnkùn tí pa ebí tí ó jé méta tí won sì fi omo kékeré tí ó fi ara pa sílè ní Epe ní ìpínlè Eko. Won ti pa gbogbo ìdílé kan run sùgbón won fi omo kékeré ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon egbé òkùnkùn Badoo ti pa Ebí tí ó jé méta ní Epe ní ìpínlè Eko .
Àwon omo egbé òkùnkùn tí pa ebí tí ó jé méta tí won sì fi omo kékeré tí ó fi ara pa sílè ní Epe ní ìpínlè Eko. Won ti pa gbogbo ìdílé kan run sùgbón won fi omo kékeré ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ejò nlá kan (paramólè) tí won pa ní agbègbè mi láìpé ní àró yí.
Ní àárò yí nígbà tí mo ti setán láti ma lo sí ibi isé ni mo pàdé àwon ògbéni yí, tí won n yo látàrí wípé won pa ejò, tí mo rò wípé paramólè ni, tí won sì ti gbèrò ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìyá omo Davido, Amanda, ti se ayeye ojó ìbí fún Davido nígbà tí ó pé odún márùnlélógún (25).
Amanda, tí ó n gbé ní Atlanta tí ó jé ìyá omo olórin orílè èdè Nàíjíríà, Davido, pin sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-story)láti se ayeye ojó ìbí Davido nígbà tí ó pé odún márùnlélógún.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa márùnlélógójì(45) tí won sì fi ogbé sì àwon tí ô kù l’ára .
Gégé bí Sani tí ó pin se so, àwon èèyàn Bachama ní alé àná ti dojú ìjà ko àwon fúlàní ní ilé tí won ngbé ní Kwadam Shafaran ìlú kéréje kan ní Numan ti ìpínlè Adamawa. Ó kéré jù márùnlélógójì ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Flavour ti fi èbùn olórun hàn l’ára rè nínú àwòrán tí kò ti wo aso tí ó yà.
Òkan l’ára àwon isé rè ni wípé tí ó bá ti e ò bá ti è níìfé orin rè èèyàn le níìfé àyà rè, bí kò tilè ní ìkan míràn jù béè lo, ó sáà ní àyà(6 packs) ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àkolùkogbà selè léyìn tí okò tí ó kó kírètì Coca cola dànù tí ìgò sì fó ní 3rd mainland bridge.
Okò tí ó kó kírètì Coca Cola ni ó dànù ní òpópónà 3rd mainland bridge yí ó sì wó òpò kírètì àti ìgò ní orí afárá náà. Okò náà tún kolu okò kan tí a mò sí Toyota Corolla kí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on BankyW àti Adesua Etomi ti wá di tokotayà báyìí, won sì ti ti fi fi owó sí ìwé èrí ìgbéyàwó won.
Láìpé ni BankyW àti Adesua Etomi se ìgbéyàwó ìbílè won ní ìlú èkó, àwon tokotayà ti wá t’owó bo ìwé èrí ìgbéyàwó wo, won ti di oko àti aya . Won ti se ìgbéyàwó alárédè báyìí. Èyí da ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Zion Ayo Balogun ; Wizkid so omo rè okùnrin tí Jada pollock bí fún ní orúko.
A gbó láìpé la gbó wípé Wizkid ti kí omo tuntun káàbò tí alákoso rè, Jada Pollock bí fun. Òótó ni èyí, Wizkid ti ri dájú wípé omo òun ni , ó sì ti so omo náà l’órúko “Zion ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on “Ó ye kí obìnrin náà ní ànfààní àti fé okùnrin Mérin” òdóbìnrin mùsùlùmí yí ló so béè.
9Ò n lò èro ayárabíàsà (Twitter) tí a mò sí Halima ni òpò ti takò látàrí wípé ó so wípé ó ye kí won gba obìnrin náà láyè kí won fé ju okùnrin kan lo. Ní òtító olórun ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán Adesua Etomi níbi ayeye ìgbéyàwó ìsènbáyé rè.
Òsèré tí ó gbajúgbajà, Adesua Etomi tún yo ní àrà òtò, sé e mò wípé òtò l’omo oba n rìn . Ó ti è ti rewà jù òun gan ni a ò bá ma pè ní Òkín l’áwùjo ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more