Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè ...
Read More »Olúbàdàn kìlò kí won má se jàgídíjàgan bí odún egúngún se fé bèrè.
Gégé bí odún egúngún odoodún se ma bèrè l’óla, ojó ajé, ní ìlú Ibadan, ní ìpínlè Oyo, Olúbàdàn ti ilè Ibadan, oba Saliu Akanmu Adetunji ti pè fún àláfíà láti òdò àwon eléégún àti àwon tí ó ń tèle tí ...
Read More »Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè
Àwòrán láti owó omo oòduà rere. Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè (a fé béè, èrín yakata). Ta ló tún n’ìfé àwòrán láti ìjìnlè ìlú yorùba? N’ísàlè ni àwòrán àjò lo sí ìlú Iseyin ...
Read More »Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.
Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè Obafemi ...
Read More »Ìjoba ìpínlè Èkó dá àwon òsìsé KAI dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won.
Ìjoba ìpínlè Èkó, lábé àse Gómìnà, láti jé kí ìlosíwájú bá ètò ìlera ti dá àwon òsìsé KAI (kick against indiscipline) dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won. Ìgbésè náà, gégé bí ìjoba ìpínlè náà, jé òkan lára ìsàkóso ...
Read More »Olólùfé gbajúgbajà olórin Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.
Àwon olólùfé gbajúgbajà olórin tí a mò sí Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re. Davido le jé eni tí àwon ènìyàn féràn sùgbón ìyan kò so pé ...
Read More »Àyàngbàjù! Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Evans pe ògá olóòpá l’éjó,
**Àti Àwon Méta Míràn Látàrí Àtìmólé Rè Ní Gbogbo Ìgbà. Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Chukwudumeme Onuwuamadike tí ìnagije rè ńjé Evans, ó ti pe ògá olóòpá l’éjó, tí orúko rè ńjé Ibrahim Idris àti àwon méta míràn ní ilé ejó gíga ti ...
Read More »Oko mi fi mí sílè nítorí pé mi ò tí bímo. Okàn mi ń pòrúrú… Egbàmí!.
…Mi ò ti è mo bí mo se fé bèrè. Ó dàbí kí ń parí gbogbo rè. Oko mi sèsè fi mí sílè torí mi ò tíì bímo àti wípé kò fé kí won gba àtò rè àti eyin mi ...
Read More »Àwòrán ilé-ìwòsàn Giginju àti irinsé orísirísi ti ilè Kano tí ó jé bílíònù lónà méji àti egbèrin néírà (₦2.8 billion)
Gómìnà ìjoba ìpínlè Kano ti ra irinsé ńlá fún ilé-ìwòsàn Giginju rè tí ó sèsè kó tán ní ìpínlè Ìjoba náà. Àwon irinsé náà ni 1.5Telsa Magnet Resonance Imaging, MRI machine, tí ó rà ní owó tí ó tó mílíònù ...
Read More »Arákùnrin kan se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Èkó.
Arákùnrin kan ní orílè èdè Nàìjíríà tí a mò sí Jefferson Uwoghiren, se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Edo. Arákùnrin náà tí kò so ohun tí ó fé fi eranko afayàfà náà se, ni ...
Read More »