Anamoyayà (civil defence officer) ni àwon Fulani darandaran pa ní ìjoba ìbílè Guma ní ìpìnlè Benue ni won ti sín pèlú òpòlopò omijé. Àwon emèwà rè ti sin ín tomijé tomijé.
Read More »Arákùnrin kan tí ó jé ígbó àti arábìnrin òyìnbó yí se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.
Arákúnrin tí ó jé ígbò yí ti se ayeye ìgbéyàwó ìbílè alárinrin, tí ó sì ti fé ìyàwó rè òyìnbó n’ísu l’ókà. Gégé bí ìgbéyàwó náà se wáyé ní ojó ketàdínlógún osù kejì odún yí (17/2/2018) , a rí àwòrán ...
Read More »Divination “Kínni Ifá wí?” (What did Ifa say?)
Medium: Ballpoint pen on paper
Read More »Chanting to Ọ̀ṣun Ṣẹ̀ngẹ̀ṣẹ́ Awẹ’dẹwẹ’mọ
Orúkọ Àpọ́nlé àwọn Obìnrin (Yoruba descriptive female names)
Aya = Wife Ìyá Afin = Queen Ayaba = Queen Yèyé Ọba = Queen mother Olorì = King’s wife Omidan =Beautiful woman Ọmọge = Young fashionable woman Ìyàwó = Wife Erelú = Female Chief Ìyálọjà = Market Leader Ìyá Àdínnì ...
Read More »Ṣàngó Arabambi by Adébóyè Adégbénró
Alaafin Of Oyo Warns Ifa Priests Against ill-gotten Wealth, Dubious Characters
The Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi 111 on Friday warned priests of Ifa traditional religion against desperation for ill-gotten wealth capable of bringing the cherished Yoruba culture and traditions into disrepute before foreigners. Oba Adeyemi gave the warning ...
Read More »DISCLAIMER: Yoruba Tradition Elders Committee on Oba Bolu Fatunmise
Yoruba Tradition Elders Committee decided to issue another release on Oba Bolu Fatunmise. As Oba Bolu Fatunmise has decided to reject Irunmole and embraced Jesus as he rightly stated in the video released to the public, we are now advising ...
Read More »E wo Nkan ti Obesere so Nipa Pasuma Ati Awon Osere Oni Fuji miran !
Gó́mìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Akínwùnmí Àmbọ̀dé ju ọwọ́ lu òfin fún ìpamọ́ àti ìgbéga èdè Yorùbá
Aàrẹ Ọ̀nà Kakanfo, Ọ̀túnba Gàní Adams ti wọn ṣe ìwúyè fún ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, oṣù kini, ọjọ́ kẹtàlá ọdún Ẹgbàáléméjìdínlógún fi ẹ̀dùn ọkàn hàn nipa bi àṣà àti ìṣe Yoruba ti fẹ́ parẹ́. Nigba ìwúyè, Ọ̀túnba Gàní Adams ṣe àlàyé ...
Read More »