Gégé bí ìròyìn se so, arábìnrin tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí tí ó wá láti Amuda Isuochi ní ìpínlè Abia, ni ó ti ń pa àwon èèyàn ìlú rè, ò n lò èro ayélujára tí ó pín àwòrán ...
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Arábìnrin tí ó ti ń pa àwon ará ìlú rè ni owó ti bà tí won sì ti fi se èsin Abia.
Gégé bí ìròyìn se so, arábìnrin tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí tí ó wá láti Amuda Isuochi ní ìpínlè Abia, ni ó ti ń pa àwon èèyàn ìlú rè, ò n lò èro ayélujára tí ó pín àwòrán ...
Read More »A TRIBUTE to the erudite Yoruba Scholar and Cultural icon who sadly left us on 17th February, 2018. Ká tó r’erin o di’igbó – k’á ró r’ẹfọ̀n ó d’ọdàn – Ka tó r’ẹ́ni bi AKINWÙMÍ ORÒJÍDÉ ÌṢỌ̀LÁ ó dàrìnàkò, ó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí Ẹ̀rọ Amóhùnmáwòrán Òpómúléró
Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi: Video Player Ọ̀jọ̀gbọ́n Olunlọyọ fi àṣà Yorùbá ti ó ti ńparẹ́ hàn ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Arákùnrin àti arábìnrin IPOB gun òkadà léyìn tí won lo se àbèwò Nnamdu kanu.
Arákùnrin àti arábìnrin IPOB gun òkadà léyìn tí won lo se àbèwò Nnamdu kanu. Àwon èèyàn yí kò kúkú ní pa mí, arákùnrin Kan tí a mò sí Nwaiwu Chiukwuebuka ni a rí pèlú arábìnrin Kan lórí òkadà Kan náà.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Murphy Afolabi se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún kerin lé l’ógójì ní Toronto, Canada.
Òsèré orí ìtàgé, Murphy Afolabi se ayeye ojó ìbí rè ní ojó mélòó séyìn. Òré àti ojúlùmò tí won jé èníyàn pàtàkí, gbajúgbajà Òsèré, adarí eré abbl ti se ayeye ìjònilójú fún omo bíbí ìpínlè Osun tí a bí ní ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Akékòó odún kerin tí ó rì s’ómi ní Yankari.
Gabriel Emmanuel Chinoso, tí ó jé Akékòó olódún mérin tí se Akékòó eka èkó onímò nípa ohun amáyé rorùn tí a mò sí electrical engineering ní ilé-èkó gíga Tafawa Balewa university, Bauchi ni ati gbó wípé òkú sí inú odò ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán okò Mercedes Benz tí Obafemi Awolowo fi se ìponlogo ní ìgbà tí ó fé lo fún Ààre orílè èdè Nàíjíríà.
Obafemi Awolowo tí ó jé ògbóntarìgì àti adarí àwon olósèlú, tí ó sì kó iPa takuntakun láti jé kí orílè èdè yí di olómìnira. Làra àwon ohun tí ó wà ní ibi tí won kó nkan ìsèńbáyé sí tí a ...
Read More »This piece shall hinge its fact on Yoruba adage that stated that…many are thieves but the one caught remains robber! When you watched sincerely on every Sunday Services in most Churches; what you will obviously noticed to your surprised admiration ...
Read More »Lolade Comments Off on Do Yoruba Serve One God Or More? Prof Sophie Olúwọlé
Do Yoruba Serve One God Or More? Prof Sophie Olúwọlé throws more light on the Pantheon
Read More »Lolade Comments Off on BBNaija: Tobi Draws Cee-C (What do you think about this Photo ?)
BBNaija housemate Tobi, showed off his creative skills when he decided to draw a picture of fellow housemate Cee-C. Guys, what do you think about the photo though?
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more