Níbáyìí, ojú wo ni òrékùnrin rè ma fi wò ó tí ó bá rí ìdí òdóbìnrin yí?. Àwòrán tí ó ti gba èro ayélujára kan ni ti obìnrin tí ó ko orúko Runtown gangan sí ìdí rè. Olórin ...
Read More »E wo ejò tí aládùúgbò mi pa, e jò wó kíni orúko rè.
Aládùúgbò mi ló pa ejò nlá yí ní kùtùkùtù òwúrò àná … Oúnje ti se.
Read More »Laura Ikeji Kanu tún yo ní àrà òtò.
Onísòwò aso àti olù gbé eré jáde, Laura Ikeji gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí ó ya ni lénu yí.
Read More »Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu.
Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè Anambra. Gbajúgbajà òsèré ...
Read More »Ajé omo Olókun.
Òrìsà ni olókun jé, a gbó wípé òun ni ó bí ajé, ó tún jé òrìsà orò àti ti ìsàlè òkun. Olókun ni ó n darí omi ó sì ní àse l’órí gbogbo ìsèdá inú omi . Olókun máa ...
Read More »Nnamdi Mpiti tí ó jé akunjú (make up artist) pín àwòrán yí .
E má jé kí èrù bà wá . Kíkùn lásán ni , àti wípé èjè iró ni ó wà níbè “.
Read More »Àwòrán tí Tonto Dikeh àti Halima Abubakar yà tí won sì rewà nínú àwòrán náà.
Òsèrè orí ìtàgé, Tonto Dikeh gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí tí òun àti òré rè tímótímó , òsèré Halima Abubakar yà.
Read More »Àwòrán bàbá àti àwon omo rè obìnrin méfà.
Àwòrán bàbá kan láti orílè èdè Nàíjíríà pèlú àwon omo rè obìnrin méfà tí ó rewà. Baba tí orí rè wú pín àwòrán àwon omo rè obìnrin méfà. Won rewà gan ni. Nse ni ó dàbi kí èmi náà ...
Read More »Gómìnà ìpínlè Eko ti sí ojú ère ” ASA AROKOLO” ní ogonlonto ní Ikorodu lánàá.
Ère tí ó bù áyà tí ó fi àsà wa hàn ní Ikorodu ni Gómìnà ìpínlè Èkó ti báwa sí lánàá.
Read More »E wo ojú Davido ní orí ìtàgé nígbà tí obìnrin náà fi ìdí rù ú .
Kí ló n selè báyìí? Se Davido sèsè n bò ni ? Obìnrin ehn ! E wo bí Davido se n wò bí eni tí ó n lo sí àjùlé òrun re . Òrò kan fun un e jò ...
Read More »