Annie Idibia fi àwòrán yí sí orí èro ayélujàra rè (instagram) tí ó rò wípé kò rewà pè é ní omobìnrin tó ” wor wor ” . Ìyá omo méji tí òhun náà sì da padà fun pé :bí ìyá ...
Read More »Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).
Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè ...
Read More »Olúbàdàn kìlò kí won má se jàgídíjàgan bí odún egúngún se fé bèrè.
Gégé bí odún egúngún odoodún se ma bèrè l’óla, ojó ajé, ní ìlú Ibadan, ní ìpínlè Oyo, Olúbàdàn ti ilè Ibadan, oba Saliu Akanmu Adetunji ti pè fún àláfíà láti òdò àwon eléégún àti àwon tí ó ń tèle tí ...
Read More »Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè
Àwòrán láti owó omo oòduà rere. Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè (a fé béè, èrín yakata). Ta ló tún n’ìfé àwòrán láti ìjìnlè ìlú yorùba? N’ísàlè ni àwòrán àjò lo sí ìlú Iseyin ...
Read More »Hundreds of artists mock Trump in Tehran cartoon competition
Trumponium and Putinita?!
Between Alaafin & Elders Of Yoruba Religion Over Oba Ifa Adimula Of S. America Title
Elders of Traditional Religion worshipers under the aegis of the Concerned Committee of Yoruba Traditional Culture and Faith Ambassadors have stood in defence of three Ifa priests accused of impersonating the Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, and extorting some ...
Read More »Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.
Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè Obafemi ...
Read More »Ìjoba ìpínlè Èkó dá àwon òsìsé KAI dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won.
Ìjoba ìpínlè Èkó, lábé àse Gómìnà, láti jé kí ìlosíwájú bá ètò ìlera ti dá àwon òsìsé KAI (kick against indiscipline) dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won. Ìgbésè náà, gégé bí ìjoba ìpínlè náà, jé òkan lára ìsàkóso ...
Read More »Olólùfé gbajúgbajà olórin Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.
Àwon olólùfé gbajúgbajà olórin tí a mò sí Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re. Davido le jé eni tí àwon ènìyàn féràn sùgbón ìyan kò so pé ...
Read More »