Posita wagba okore kun igboro ilu Port-Harcourt
Read More »
ayangalu Comments Off on Posita gbigba okore pada Kun ilu Port-Harcourt Egba ni eleja
Posita wagba okore kun igboro ilu Port-Harcourt
Read More »ayangalu Comments Off on Eyin eniyan e wo E-moni(E-money) ninu photo titun re.
Alaga ti Ẹgbẹ eka marun apapo , wuni ninu poto re titun ti o sese ya.
Read More »ayangalu Comments Off on Tonto Dikeh ki Mercy Johnson pe ‘oku orire fun ipo titun ti Gomina Kogi sese yan si’.
Awuyewuye ija ti oun lo laarin awọn oṣere Tonto Dikeh ati Mercy Johnson, Tonto Dikeh ti toro aforiji lori awọn gbólóhùn o ṣe nipa ọmọ rẹ ati awon oro miran to ti so ni odun die seyin. Mercy Johnson gba ebe ...
Read More »Awon ‘SON’ (Standards Organisation of Nigeria) ti mu ogbeni akeruwole ti oun ta aye deru Kosimetik ati ọti-waini ti se ayipada awọn ogun ti ọjọ ti lo lori wọn ati ti o nri titun ọjọ lori wọn, ni eyi ti ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ” Ẹran-àmúsìn – Ọdẹ peku-peku” –
Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á pa kẹ́kẹ́ titi dé ori ...
Read More »ayangalu Comments Off on “Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́ Àṣejù
Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o tiraka lati pari ...
Read More »ayangalu Comments Off on Omo Yo’ooba: Se Looto Ni?
Se beeni abi be ko ?
Read More »ayangalu Comments Off on Who is Elenini ?
Following my last post on “who is Elenini”, here is my own submission. My senior sister, Olayinka Moussa described Elenini as antagonist. The President of International Council for Ifa Religion, Oloye(Prof). Idowu Odeyemi said, “not all critics are enemies, not ...
Read More »ayangalu Comments Off on Photo of the day !
Traditional festival in northern part of Nigeria, Nassarawa state, Nigeria!!! Is this not African spirituality??? I love this!!!
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Fun Wa Latari Bi A Se Mo Ise Aburu Ti Awon Elenini Nse Lati Ma Fe Jeki Eniyan Se Rere Ati Saseyori Nile Aye,
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku imura toni, mo gbaladura laaro yi wipe gbogbo awon ota ti won ba sope ako ni se rere yio di gige kuro lori ile alaaye loni ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more