E MAA WI TELE MI : ……… *Owo ko ni ri mi sa. *Oju owo ko ni pon mi. *Ojo ibukun mi ko ni di ojo abuku. *Alaaanu mi ko ni ko’yin si mi. *Edumare ma je ki n teni ...
Read More »Iwure Osu Tuntun 01-05-2016
E MAA WI TELE MI : ……… *Osu karun-un yii, osu ire owo ni fun mi. *Osu ire ile kiko ni fun mi. *Osu ti maa ra oko ayokele. *Osu igbega lenu ise mi ni. *Osu idunnu ni yoo je ...
Read More »Ibeere Toni
Egbo eyin o ogbon,…nje oda ki Iyawo ile o mo ko orun fun okore ? ….tabi ki oko naa o ko fun Iyawo re?……. Iru nkan wonyi se o ma ndin Ife Ku ni abi oma tubo mufe gbile si???????????
Read More »Oko mi ati iya re loba aye mi je
Akole oke yi lo se apejuwe oro arabinrin kan , eyi to fi esun kan iya oko re wipe o gba arisiki oun fun omo (oko re) Nigbati obinrin yi so oro , emi bi leere wipe SE OKO SAA ...
Read More »Iwure Owuro Ipari Osu
E MAA WI TELE MI : ….. *Airije-airimu nile aye mi ti dopin. *Ibanuje ninu aye mi ti dopin. *Ijakule ninu aye mi ti dopin. *Ise mi ko ni dojuru *Ogun aye ko ni borii mi. *Oju owo ko ni ...
Read More »Kabiesi sango o,arabambi arigba ota segun !
Sangiri Lagiri Olagiri kaka figba edun bo Inan Loju Inan lenu Oloju orogbo eleeke obi A tu won ka nibi tiwon gben danan iro….Sango onikoso ooo Happy ose sango day to all onisese here in Nigeria and diaspora?❤️?❤️?????
Read More »Ritual painting By Ifa professor Moyo
ỌBALÚAYÉ ritual, painting and photography by Prof. Moyo Okediji See full painting after the page break bellow.
Read More »“OPELE loyo tan to dakun dele
Adifafun perengede Tinseyeye Ojumomo, Ojumotomo wa loni Ojumo aje ni koje fun gbogbo wa Ojumo Ire gbogbo ni ko je fun wa Perengede Iwo ni yeye Ojumomo Ojumo Idun nu ni eni ati gbogbo ojo maje fun gbogbo wa……. ASHEE ...
Read More »Orewa kilode kilo fa ironu?
Bao ku ise o tan toripe yoruba bo won ni airise koni kapada si orun-alakeji tiko basi oko (farm) ao si ma re idale(travel) ko si eni to la laye yi tiko ni ri nkan wi, amo saa ti oro ...
Read More »Fi ere si temi Eledumare
Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe ...
Read More »