I saw one disgracing, sad and misleading video on YouTube today. One Olorisa obatala from Osogbo who the Muslims claimed to have converted from Orisa worship to becoming a muslim. This happened maybe 4days ago. Let me start by saying ...
Read More »QOTD: What is English name of Ijabe
Final answer ?
Read More »British Soldier Grandson, Mark Walker To Return Looted Items From The Kingdom of Benin
The grandson of a British soldier who took part in the looting of Benin City in the late 19th century is returning items his ancestor took in a move experts say opens up a debate in what could happen to ...
Read More »Ìdí tí Oluwo fi kọ Olorì rẹ̀ sílẹ̀ rèé
Ìdí tí Oluwo fi kọ Olorì rẹ̀ sílẹ̀ rèé Fẹ́mi Akínṣọlá Kábíèsí Oluwo ti ìlú Ìwó, Ọba Abdulrosheed Adewale ti kọ Olorì rẹ̀ Chanel Chin sílẹ̀. Agbẹnusọ fún Kábíèsí ọ̀hún, Alli Ibrahim fi ìdí ọ̀rọ̀ náà mulẹ fún akọ̀ròyìn. Bí ...
Read More »Àhes̩o̩ ò̩rò̩ ni ikú Babangida
Aheso oro ni iku BabangidaYinka AlabiAriwo iku ajagunfehinti to o tun je Aare Ologun ni orileede yii tele ri, Ibrahim Babangida ni o gbode Kan.Ariwo yii po lori ero ayelujara lati idaji oni sugbon Ogbeni Kazim Afegbua ni iro ni. ...
Read More »Èèmọ̀ rè é o !, Ìyàwó àfẹ́sọ́nà kú sínú Kànga, nígbeyàwó kọ̀la
http://iroyinowuro.com.ng/2019/12/14/eemo-re-e-o-iyawo-afesona-ku-sinu-kanga-nigbeyawo-kola/ Èèmọ̀ rè é o !, Ìyàwó àfẹ́sọ́nà kú sínú Kànga, nígbeyàwó kọ̀la Fẹ́mi Akínṣọlá À fi ká kún f’áàdúà kí ọjọ́ ayọ̀ ẹni ó má padà dọjọ́ ìbànújẹ́.Kí èṣù ó sì má ráàyè gbọjọ́ ẹ̀yẹ ẹni . À bí ...
Read More »Ìlé ẹjọ́ rọ Obalufẹ̀ ti Ilé Ifẹ̀ lóyè
http://iroyinowuro.com.ng/2019/12/15/ile-ejo-ro-obalufe-ti-ile-ife-loye/ Ìlé ẹjọ́ rọ Obalufẹ̀ ti Ilé Ifẹ̀ lóyè Fẹ́mi Akínṣọlá Ó dà bí ẹni pé awuyewuye ìfinijoyè , ìyọnilóyè sì ń tẹ̀ẹ́wájú o , bí Ilé ẹjọ́ gíga ti ìpínlẹ Ọṣun ti pa á láṣẹ fún Ọbalúfẹ̀. ti ìlú ...
Read More »Ọ̀pọ̀ èèyàn ló sá fún mi nígbà tí mo dùbúlẹ̀ àìsàn…Taiwo Hassan
http://iroyinowuro.com.ng/2019/12/12/opo-eeyan-lo-sa-fun-mi-nigba-ti-mo-dubule-aisan-taiwo-hassan/ Ọ̀pọ̀ èèyàn ló sá fún mi nígbà tí mo dùbúlẹ̀ àìsàn…Taiwo Hassan, Ògògó Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí ẹyìn ọ̀rọ̀ ò bá ì pọ́n, ẹnìkan kìí sí i ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí bí gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò,n nì, ...
Read More »I love Oodua wins
A poll between I love Yoruba or I love Oodua took place and latter won by a large margin. Ooduarere.com favourite cap on Twitter profile pic and facebook will be replaced with I love Oodua.Other social media profile picture will ...
Read More »