Arewà obìnrin kan ni ó gbé o n je omo (oyàn) rè han nínú àwòrán òun àti oko àfésónà kí won tó se ìgbéyàwó. Arábìnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà ní ó fi orí oyàn hàn níbi àwòrán ...
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó.
Arewà obìnrin kan ni ó gbé o n je omo (oyàn) rè han nínú àwòrán òun àti oko àfésónà kí won tó se ìgbéyàwó. Arábìnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà ní ó fi orí oyàn hàn níbi àwòrán ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.
Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won. Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won. Omokùnrin kan láti orílè ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ifa-lafinimona: Ifa, the Pathfinder.
Ifalafinimona Ifa is the pathfinder embrace it as you would your belover.
Read More »ayangalu Comments Off on Iba Eleiye
Orunmila wi Awo tan.Ifa mi Awo ku mi Bara Agbonmiregun.Ifa ni nibo ni Awo ku si?Mo ni o ku awon Ajagaruwa.Mo ni o ku awon Alsgbede orun ko mero ileke.Mo ni o ku Okoko sii wele. Ifa lo di obiri Mo ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on The Ogun Festival In Omupo, Kwara State, Nigeria – Photos
Bellow is the photo of Elemoso Ogun of Ijagbo Land and Oluode Aluwo Of Offa at the Ogun Festival In Omupo, Kwara State, Nigeria. See another photo bellow
Read More »ayangalu Comments Off on Annual Ifa Festival: Save the date!
Please sing along with me as follows:- Mi o fi sawada mo wi o, mi o fi sawada Bi mo t’ayewa onifa ni N o seMi o fi sawada mo wi o This is not a joke, I declare, I am ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe.
Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe. Owó sìnkú àwon agbófinró ti orílè èdè Nìjíríà ti te Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe ní ònà gbòòrò. Nígbà tí ó ní irú opolo láti se èyí, kílódé tí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ogbè Até
Owó òtún mi ni mo fi n gba ire Adífáfún Sará Sará N’ílé olódùmarè la gbé n báwon Lóri orí eni òré òhun tìmùtìmù rere Àtélewó mi òsì Ni mo fi n gba ìfà Adífáfún Sèbí Sèbí N’ílé olódùmare ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ori mi Apeere
Ka ji ni kutukutuKa mu ohun ipin ko’pind’Ifa fun Olomo-ajiba’re-padeEmi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pinEmi ni mo ba ire pade nigba gbogbo ori mi apeereAteteniranAtetegbeni ju OrishaKo si Orisha ti danni gbe leyin ori eniOri ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹyọ De Ọlọ́bẹ̀ Oko
Ọ̀̀rọ̀ mi gbogbo ka sàì yọ́ ikin nínú gẹ̀ẹ̀rẹ̀gẹ̀ Mo sé ní ìwúre ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ẹ̀sẹ̀ tí a sẹ̀ Ọlọ́run, osó,ajẹ́ àbí ènìyàn bi tiwa ni, tó ń fa ìdíwọ́ kan àbí ìkejì, mo súre fún wa ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more