Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá. Gbajúgbajà àti ìlú mòóká òsèré tí a mò sí ìyá ìjo, Tonto Dikeh, ti gbe lo sí orí èro ayélujára Ínsítágírámú láti jé kí ámò wípé nse ...
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá.
Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá. Gbajúgbajà àti ìlú mòóká òsèré tí a mò sí ìyá ìjo, Tonto Dikeh, ti gbe lo sí orí èro ayélujára Ínsítágírámú láti jé kí ámò wípé nse ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on KÁDÀRÁ Ò GBÓÒGÙN
Adáni wáyé ti dáni sáyé ná. Káwayé máyà tó sayé dàwáàlọ. Òréré layé kò see wò tán. Àyàfi ká gba kádàrá lókù. Kádàrá ò seé kọ̀ láìgbà. Ádíá f’ẹ́ja tó f’ibú selé. Ádíá f’ọ́pọ̀lọ́ tó f’òkè s’ebùgbé. Ọ̀pọ̀ló f’omi s’elé, ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Olódùmarè mà tóbi lóba ooo.
Olódùmarè mà tóbi lóba ooo. Kíni olórun olódúmarè kò le se tán, Olódùmarè tó dá ayé òhun òrun tí ó sì so òrò sí órìlè ayé, òrò náà á máa jé Ifá tí ó fi rán òrúnmìlà baba àgbónìrègún. Òdú ...
Read More »Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára. A gbó wípé kò sí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òsèré Yvonne Jegede àti Oko è kí omo tuntun káàbò tí ó tún jé àkóbí won.
Gbajúgbajà Òsèré Yvonne Jegede Fawole àti oko rè dun nú nígbà tí won bí omo tuntun tí ó tún jé Àkóbí won. Bí ó ti lè jé wípé a kò tí mò bóyà ako ni àbí abo sùgbón a mò ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ká ṣojú ẹni Ká sẹ́yìn ẹni Orúkọ tí à á pe ìránṣẹ́ (ìbò) .
Òtítọ́ wọn kò sí láyé mọ́ Aṣẹ̀yìn deni wọn kò wọpọ̀ Àbàtà ńlá abojú dẹ̀gun dẹ̀gun Ká ṣojú ẹni Ká ṣẹ̀yìn ẹni Àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ní ọmọ ìkọ́fa Ilé Àgbọnnìrègún Baba kọ́won ní dídá ọwọ́ Wọ́n mọ̀ ọ́n dá Ifá kọ́won ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Akékòó okùnrin tí ó ti wà ní ìpelè tí ó parí ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìlú Oko ni won yìnbo fún tí ó sì kú.
Arákùnrin kan ni won yìn ìbon fún ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìjoba ní Oko ní ìpínlè Anambra. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé tí gbogbo èèyàn mò sí ‘ De moon’ jé Akékòó féè pari tí ó sì jé ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú.
Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú. Gbajúgbajà olórin àti ìlú mòóká olórin tí gbogbo ayé mò sí Wizkid àti Kiss Daniel ya àwòrán papò nínú okò ojú òfurufú aládani. Nse ni ó dàbí eni wípé won fé ...
Read More »ayangalu Comments Off on The process of Òrìsà initiation
Òrìsà initiation is a process that opens you up to the power and higher relationship with your guardian Òrìsà and other Òrìsà. Initiation brings new life, get rid of negativities, wealth, children, favour, protection, breakthrough and all the Ire. Yoruba ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu, Otua rete
Looking at Odu, Otua rete cast for today’s Ose Ifa, I conclude that fulfilling the obligation is necessary as a way of thanksgiving. Just listen to the sacred message from the Odu as follows:- Alayonbere abiru gbooro Adifa fun Modupeola ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more