Omokùnrin odún méèédógún yí gba máàkì tí ó pò jùlo nínú ìdánwò àti wo ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó sì gba púpò jùlo nínú WAEC. Omokùnrin yí gba àmì A nínú gbogbo ìdánwò tí Ó se fún WAEC tí Ó ...
Read More »ÈDÈ YORÙBÁ
ÈDÈ YORÙBÁ Èdè Yorùbá ṣe pàtàkì; Ó ṣe kókó. Ẹ̀yin ọmọ Oòduà, Ẹ jẹ́ ká máa rọ́jú s’èdèe wa. Èdè òǹluko kọ́ l’èdèe Yorùbá. Èdè tó gba’yì tó gb’ẹ̀yẹ ni. Àìkọ́mọ l’áhọ́n-ìbílẹ̀, Ní sábàbí ìwà ọ̀yájú. Ọmọ yín jí ní ...
Read More »Yoruba Family
Written by Akin Fagbo Aiyejin Family occupies a pre-eminent place in the live of Yoruba; regardless, every Yoruba child is born into a home, which is a part of a compound or a clan. Family members always trace their descent ...
Read More »Some names and how they came about
Some names and how they came about OSOGBO was coined out of Oso Igbo, (Bush witch). This was as a result of earlier settlers who surprisingly met a man at the Osun river and they referred to the man as ...
Read More »Won ti ojà ní Abeokuta láti fi se àpónlé fún Oba won tí ó di olóògbé.
Ojà tí ó wà ní ìlú Abeokuta ní won tì pa pátápátá ní àná, won se èyí láti fi se àpónlé Oba won tí ó wàjà eni tí a mò sí Oba Halidu Laloko (MFR) tí ó jé Agura ti ...
Read More »Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York.
Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York. Gbajúgbajà tí ó tún jé ògbóntarìgì olórin ìgbàlódé ti a mò sí Tuface Idibia tí ó wà ní orílè èdè United State báyìí fún ìrìn àjò ...
Read More »Àwon ajínigbé àti omo egbé òkùnkùn mérin ní ìpínlè River
Àwon ajínigbé mérin tí won tún jé omo egbé òkùnkùn tí ńkó da ìjoba ìbílè Eleme àti agbègbè rè láàmú ni àwon olùbódàbòbò pa . Orúko àwon tí won pa a máa jé Joe Mba tí ìnagije rè ńjé Sk ...
Read More »Alibaba tako Anthony Joshua nígbà tí ó ya àwòrán Láì wo aso tí àwon èyà ara rè sì hàn.
Anthony Joshua ní láti gbáradì fún ogun míràn báyìí ni Alibaba tí Ó jé apanilérìn-ín àti adérìn-ín pa òsónú se so nígbà tí Anthony fi aya rè hàn tí èyí sì fi hàn wípé okùnrin mésàn-án ni, òun náà sì ...
Read More »Ògún lákáayé .
Ọ̀wọ́nyán rosùn porogodo lóso, Agogo ńlá ni wọ́n fi ń fọ́ri fálágbára mu, Àtàtà ńlá ni wọ́n fi ń fọ yíìrí mọrọ̀, Adífáfún Ògún tíń gbógun lọ sí Ìgbòmẹkùn-eséji, ẹbọ lawo níkóse, Ògún ló sẹbọ sètùtù lówá kóre dé ìtùtúrú ...
Read More »Àwòrán Saraki nígbà tí won se ìpàdé pèlú Woke, Ortom àti àwon míràn ni ìpínlè Kwara.
Àwon ìgbìmò tuntun rè é, Gómìnà ìpínlè River, Nyesom Ezenwo Wike tètè dé sí Ilorin ní ìpínlè Kwara fún ìpàdé pàtàkí náà pèlú àwon ti Benue náà, Gómìnà Samuel Ortom tí ó sèsè ko ìwé láti fi egbé APC sílè ...
Read More »