Ogúnl’ógbòn àwon òdó ni won péjú níbi ayeye ojó ìbí Ààre orílè èdè Nàíjíríà télè, Goodluck Ebele Jonathan láti ba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo ogota odún. E wo àwòrán n’ísàlè .
Read More »“Mo máa já we kulè ” Wizkid kìlò fún obìnrin tí ó ní ìfé rè .
Òkan lára àwon Olólùfé obìnrin tí ó ti nífèé Wizkid ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi èhónu rè hàn wípé òun nífèé Wizkid sùgbón ó so wípé ànfààní nlá ni kí Wizkid fé òun kí ...
Read More »Arábìnrin yí ni ó ya àwòrán tí ó ti fi èro ìbánisòrò rè hàn tí ó sì gbàgbé wípé òrá ìdáàbòbò (condom) tí won ti lò wà ní àrin esè rè.
Arábìnrin yí ni ó ti fún àwon èèyàn ní òrò so léyìn tí ó fi èro ìbánisòrò rè tí ó jé aláwò pupa hàn nínú ilé ìtura tí ó wà làímò wípé òrá ìdáàbòbò èyí tí won ti ...
Read More »Emma Nyra dùn nínú aso ìwè tí ó wò ní Dubai .
Olórin orílè èdè Nàíjíríà, Emma Nyra ti gbìmò láti fi èbùn tí olórun fun han gbogbo àgbáyé lórí èro ayélujára ( Instagram). Olórin tí ó n lo ìsinmi rè lówó ní Dubai ti pín àwòrán tí ó yà ...
Read More »Yemen – Appeal to President Putin
by Peter Koenig Dear President Putin, Yemen, a peaceful and extremely poor country is being slaughtered, literally slaughtered by the Saudis, with the full weapons, funding and political support of the United States of America and the UK. The rest of ...
Read More »Peter okoye se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún mérìndínlógójì pèlú Omotola, Ebí àti òré.
Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr. P ti lé odún kan ní àná ó sì se ayeye ojó ìbí náà pèlú àwon ebí àti òré ní ilé rè. Gbajúgbajà òsèré, Omotola náà wà níbè.
Read More »Omobìnrin tí kò ti dàgbà púpò ni àwon olùdábòbò yin ìbon pa ní Agbonchia , ní ìpínlè Anambra .
Gégé bí èni tí ó pin sí orí èro ayélujára (Facebook) focuselema, àwon agbófinró ti jèbi pípa omobìnrin yí (tí àwon míràn ní okúnrin ni ) ti kú sí Agbonchia . A kò mo ohun tí ó fa ...
Read More »Kenneth Okonkwo àti omo rè yo ní àrà òtò.
Bí eni tí ó pin se so wípé . “Àwon òbí ní láti sóra fún àwon nkan tí won bá n se n’íwájú àwon omodé nítorí won n wò wá”.
Read More »Won dí afárá Niger nítorí ètò ìdìbò tí ó n lo lówó ní Anambra.
Afárá tí kò fi ìgbà kan dúró tí ni won ti tì látàrí ìdìbò tí ó n lo lówó ní Anambra.
Read More »Nabila Fash pe àwon obìnrin níjà bí won bá le ya àwòrán làì kunjú bí ti tò òun.
Bí Nabila, ìyàwó olórin kan, Oritsefemi se pín àwòrán tí kò ti kunju tí ó so wípé òun yà léyìn ìdárayá ní òwúrò àná.
Read More »