Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn coronae̩i Aja to rele Ekun to bo, o ye ki a kii ku ewu.Gbajugbaju oludasile ileese redio ati telifison Ray power ati AIT ni o se alabapade ajakale arun coronavirus ni nnkan bii ose meji to ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn covid-19
Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn coronae̩i Aja to rele Ekun to bo, o ye ki a kii ku ewu.Gbajugbaju oludasile ileese redio ati telifison Ray power ati AIT ni o se alabapade ajakale arun coronavirus ni nnkan bii ose meji to ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjọba àpapọ̀: À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ, kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀
À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ ,kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀- Ìjọba àpapọ̀ Iléeṣẹ́ tó wà fún ìpèsè ohun ìrànwọ́ nílẹ̀ wa ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yìí nínú àtẹjáde kan tó fisíta lójú òpó abẹ́yefò Twitter ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni
Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni Bá a kú làá dère, èèyàn kò sunwọ̀n láàyè.Gómìnà Ṣèyí Mákindé ti sàpèjúwe ọ̀kan lára àwọn Kọmíṣọ́nnà rẹ̀, Kẹhinde Ayọọla tó papòdà ní Ọjọ́bọ, ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn ún ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ewì Toni: Ìwà rere
*Ìwà rere*Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà’bàjé ní jẹ́ k’ọ́mọ o j’ìyàẸwúrẹ́ ya aláìgborànÀgùntàn jẹ́ oníwàpẹ̀lẹ́Adígbánnákú ṣẹ̀yìn gákangàkan Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà rere lẹ̀sọ́ ènìyànÌwà rere ni òbí ní,tí wọ́n fi ń ǹpé ní òbí rereÒbí rere ló le kọ́mọ ní’wà rereÒbí ...
Read More »Lolade Comments Off on There is traditional cure for COVID-19, says Alaafin
The Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, has said there is traditional cure for COVID-19 pandemic. He spoke in his palace while presenting to the public, a book written on the late Yoruba music genre of Apala, Ayinla Wahidi, popularly ...
Read More »Lolade Comments Off on Top Ten Hospitals In Nigeria
Listed here are the top Ten hospitals in Nigeria based on world webometrics ranking, It’s mandatory we all know the most effective hospitals around us especially since Coronavirus statistics is increasing by the day. Below are a few of the ...
Read More »scully009 Comments Off on Happy #Bitcoin Halving 2020
Happy Bitcoin Halving 2020 in advance. Read more about Bitcoin halving here.
Read More »scully009 Comments Off on ‘Nouriel Roubini throw jabs, says Bitcoin is a total scam — again’
Nouriel Roubini says Bitcoin is a total scam. Bitcoin priceWe closed the day, May 10 2020, at a price of $8,756. That’s a worrying 8.70 percent decline in 24 hours, or -$834.73. It was the lowest closing price in nine ...
Read More »ayangalu Comments Off on Èeyàn 239 míràn ni àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Èeyàn 239 míràn ni àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà À fi kí Ọlọ́run sàánú wa lórí àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí kòrónáfairọ̀ọ̀sì yìí tó ń gbomi lójú t’olórí t’ẹlẹ́mù, bí Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí tún kéde àwọn ènìyàn tuntun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ kó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie
Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie Àwámárídìí ni iṣẹ́ Elédùwà, ṣùgbọ́n ọmọ èèyàn lọ́pọ̀ ìgbà má a ń fẹ́ tú fín ìn ìdí i kóòkò láti mọ kín gán án ní ń gbénú-un rédíò fọhùn. Bí ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more